Thu Jun 27 2019 09:27:29 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 09:27:29 +01:00
parent 0c2e5ee231
commit 814f78251f
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 8 Kódà bí ó bájẹ́ àwa tàbí ángél ìkan láti ọ̀run lóbá kéde ìhìnrere míràn fún n yín tí ó yàtò sí èyí tí a ti kéde fún n yín, jẹ́ kí odí ẹni ìfiré. \v 9 Bí a ti ṣe sọ tẹ́lẹ̀, béèni mo tún sọ fún un yín nísinsìnyí, "bí ẹnikẹ́ni bá kéde ìyìnrere tí ó yàtọ̀ sí èyí tí ẹ gbà, kí odí ẹni ìfiré." \v 10 Ǹjé èmi a ńwá òùntẹ̀ ti ènìyàn tàbí tí Ọlọ́run bí? Ṣé èmi ń wá láti tẹ́ ènìyàn lórùn? Tí èmi bá sì ń wá láti té ènìyàn lórùn, èmi kìí ṣe ìránsẹ́ ti Krístì. \v 8 Kódà bí ó bájẹ́ àwa tàbí ángéli kan láti ọ̀run ló bá kéde ìhìnrere míràn fún yín tí ó yàtò sí èyí tí a ti kéde fún yín, jẹ́ kí ó dí ẹni ìfiré. \v 9 Bí a ti ṣe sọ tẹ́lẹ̀, béèni mo tún sọ fún un yín nísinsìnyí, "bí ẹnikẹ́ni bá kéde ìyìnrere tí ó yàtọ̀ sí èyí tí ẹ gbà, kí dí ẹni ìfiré." \v 10 Ǹjé èmi a ńwá òùntẹ̀ ti ènìyàn tàbí tí Ọlọ́run bí? Ṣé èmi ń wá láti tẹ́ ènìyàn lórùn? Tí èmi bá sì ń wá láti té ènìyàn lórùn, èmi kìí ṣe ìránsẹ́ ti Krístì.