Thu Jun 27 2019 09:25:29 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 09:25:29 +01:00
parent 6e224de3c0
commit 0c2e5ee231
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 3 Ore ọ̀fẹ́ àti àláfíà fún yín láti ọ̀dọ Ọlọ́run Baba wa àti Jésù Krístì Ọlọrun, \v 4 ẹni tí ó fi ara rẹ̀ sílẹ̀ nítorí ẹ̀sẹ̀ wa kí ó le gbàwá lọ́wọ́ ìgbà búburú yìí, ní ìbáámu pẹ̀lú ìfẹ́ Ọlọ́run Baba wa, \v 5 tirẹ̀ ni ògo láí àti láí láí. Àmín.
\v 3 Ore ọ̀fẹ́ àti àláfíà fún yín láti ọ̀dọ Ọlọ́run Baba wa àti Jésù Krístì Ọlọrun, \v 4 ẹni tí ó fi ara rẹ̀ sílẹ̀ nítorí ẹ̀sẹ̀ wa kí ó le gbàwá lọ́wọ́ ìgbà búburú yìí, ní ìbáámu pẹ̀lú ìfẹ́ Ọlọ́run Baba wa, \v 5 tirẹ̀ ni ògo láí àti láíláí. Àmín.

View File

@ -1 +1 @@
\v 8 Kódà bí ó bájẹ́ àwa tàbí ángélì láti ọ̀run lóbá kéde ìhìnrere míràn fún n yín tí ó yàtò sí èyí tí a ti kéde fún n yín, jẹ́ kí odí ẹni ìfiré. \v 9 Bí a ti ṣe sọ tẹ́lẹ̀, béèni mo tún sọ fún un yín nísinsìnyí, "bí ẹnikẹ́ni bá kéde ìyìnrere tí ó yàtọ̀ sí èyí tí ẹ gbà, kí odí ẹni ìfiré." \v 10 Ǹjé èmi a ńwá òùntẹ̀ ti ènìyàn tàbí tí Ọlọ́run bí? Ṣé èmi ń wá láti tẹ́ ènìyàn lórùn? Tí èmi bá sì ń wá láti té ènìyàn lórùn, èmi kìí ṣe ìránsẹ́ ti Krístì.
\v 8 Kódà bí ó bájẹ́ àwa tàbí ángél ìkan láti ọ̀run lóbá kéde ìhìnrere míràn fún n yín tí ó yàtò sí èyí tí a ti kéde fún n yín, jẹ́ kí odí ẹni ìfiré. \v 9 Bí a ti ṣe sọ tẹ́lẹ̀, béèni mo tún sọ fún un yín nísinsìnyí, "bí ẹnikẹ́ni bá kéde ìyìnrere tí ó yàtọ̀ sí èyí tí ẹ gbà, kí odí ẹni ìfiré." \v 10 Ǹjé èmi a ńwá òùntẹ̀ ti ènìyàn tàbí tí Ọlọ́run bí? Ṣé èmi ń wá láti tẹ́ ènìyàn lórùn? Tí èmi bá sì ń wá láti té ènìyàn lórùn, èmi kìí ṣe ìránsẹ́ ti Krístì.