Thu Jun 27 2019 22:25:51 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
8b23c0d954
commit
ef02204ae3
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 11 Nítorínaáà ẹ rántí wípé nígbàkan rí, ẹ jẹ́ kèfèrí nínú ara. A pè yín ní "aláìkọ̀là" nípa ohun tí a pè ní "ìkọ̀là" nínú ara tí a se nípa ọwọ́ ènìyàn. \v 12 Ní ìgbànáà ẹ wà ní ìyapa pẹ̀lú Krístì. Ẹ jẹ́ àlejò sí àwọn ara Isrẹlì. E je alejo si majemu naa ti a ti se ileri. E ko ni ireti kan fun ojo ola, E si wa laini Olorun ninu aye.
|
||||
\v 11 Nítorínaáà ẹ rántí wípé nígbàkan rí, ẹ jẹ́ kèfèrí nínú ara. A pè yín ní "aláìkọ̀là" nípa ohun tí a pè ní "ìkọ̀là" nínú ara tí a se nípa ọwọ́ ènìyàn. \v 12 Ní ìgbànáà ẹ wà ní ìyapa pẹ̀lú Krístì. Ẹ jẹ́ àlejò sí àwọn ara Isrẹlì. Ẹ jẹ́ àlejò sí majẹ̀mu náà tí a ti se ìlérí. Ẹ kò ní ìrètí kan fún ọjọ́ ọ̀la, Ẹ si wa laini Olorun ninu aye.
|
Loading…
Reference in New Issue