Thu Jun 27 2019 22:23:51 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 22:23:52 +01:00
parent 1b4a0e520e
commit 8b23c0d954
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 11 Nítorínaáà ẹ rántí wípé nígbàkan rí, ẹ jẹ́ kèfèrí nínú ara. A pè yín ní "aláìkọ̀là" nípa ohun tí a pè ní "ìkọ̀là" nínú ara tí a se nípa ọwọ́ ènìyàn. \v 12 Ní ìgbànáà ẹ w ni iyapa pelu Kristi. E je alejo si awon ara Isreli. E je alejo si majemu naa ti a ti se ileri. E ko ni ireti kan fun ojo ola, E si wa laini Olorun ninu aye.
\v 11 Nítorínaáà ẹ rántí wípé nígbàkan rí, ẹ jẹ́ kèfèrí nínú ara. A pè yín ní "aláìkọ̀là" nípa ohun tí a pè ní "ìkọ̀là" nínú ara tí a se nípa ọwọ́ ènìyàn. \v 12 Ní ìgbànáà ẹ wà ní ìyapa pẹ̀lú Krístì. Ẹ jẹ́ àlejò sí àwọn ara Isrẹlì. E je alejo si majemu naa ti a ti se ileri. E ko ni ireti kan fun ojo ola, E si wa laini Olorun ninu aye.