diff --git a/02/11.txt b/02/11.txt index d1b7a0b..80459b0 100644 --- a/02/11.txt +++ b/02/11.txt @@ -1 +1 @@ -\v 11 Nítorínaáà ẹ rántí wípé nígbàkan rí, ẹ jẹ́ kèfèrí nínú ara. A pè yín ní "aláìkọ̀là" nípa ohun tí a pè ní "ìkọ̀là" nínú ara tí a se nípa ọwọ́ ènìyàn. \v 12 Ní ìgbànáà ẹ w ni iyapa pelu Kristi. E je alejo si awon ara Isreli. E je alejo si majemu naa ti a ti se ileri. E ko ni ireti kan fun ojo ola, E si wa laini Olorun ninu aye. \ No newline at end of file +\v 11 Nítorínaáà ẹ rántí wípé nígbàkan rí, ẹ jẹ́ kèfèrí nínú ara. A pè yín ní "aláìkọ̀là" nípa ohun tí a pè ní "ìkọ̀là" nínú ara tí a se nípa ọwọ́ ènìyàn. \v 12 Ní ìgbànáà ẹ wà ní ìyapa pẹ̀lú Krístì. Ẹ jẹ́ àlejò sí àwọn ara Isrẹlì. E je alejo si majemu naa ti a ti se ileri. E ko ni ireti kan fun ojo ola, E si wa laini Olorun ninu aye. \ No newline at end of file