Thu Jun 27 2019 20:56:31 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 20:56:33 +01:00
parent 904c99a4dd
commit cae2b54d3c
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 19 Nínú àdúrà mi, mo béèrè wípé kí ẹ̀yin kí ó lè mọ títóbi agbára Rẹ̀ tí kó ní òsùnwọ̀n nínú àwa tí ó gbàgbọ́ gẹ́gẹ́bí síse isẹ́ títóbi nípa okun Rẹ̀. \v 20 Èyí ni òduwọ̀n agbára kannà tí Ọlọ́run fi sisẹ́ nínú Krístì, nígbàtí Ó jíi dide ninu awon oku ti o si mu ki o joko ni owo otun Re ninu awon orun. \v 21 O mu ki Krisiti joko rekoja gbogbo isakoso ati ase ati agbara, ati ijoba ati oruko ko ruko ti a le da. Kristi yoo se akoso, kii se ni aye yii nikan sugbon, koda ni aye ti mbo pelu.
\v 19 Nínú àdúrà mi, mo béèrè wípé kí ẹ̀yin kí ó lè mọ títóbi agbára Rẹ̀ tí kó ní òsùnwọ̀n nínú àwa tí ó gbàgbọ́ gẹ́gẹ́bí síse isẹ́ títóbi nípa okun Rẹ̀. \v 20 Èyí ni òduwọ̀n agbára kannà tí Ọlọ́run fi sisẹ́ nínú Krístì, nígbàtí Ó jíi dìde nínú àwọn òkú tí ó sì mú kí ó jòkó ní ọwọ́ ọ̀tún Re ninu awon orun. \v 21 O mu ki Krisiti joko rekoja gbogbo isakoso ati ase ati agbara, ati ijoba ati oruko ko ruko ti a le da. Kristi yoo se akoso, kii se ni aye yii nikan sugbon, koda ni aye ti mbo pelu.