From cae2b54d3cdd06f8334ebd3817242687bb32dbf1 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Thu, 27 Jun 2019 20:56:33 +0100 Subject: [PATCH] Thu Jun 27 2019 20:56:31 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 01/19.txt | 2 +- 1 file changed, 1 insertion(+), 1 deletion(-) diff --git a/01/19.txt b/01/19.txt index 351fc4c..b69bfb5 100644 --- a/01/19.txt +++ b/01/19.txt @@ -1 +1 @@ -\v 19 Nínú àdúrà mi, mo béèrè wípé kí ẹ̀yin kí ó lè mọ títóbi agbára Rẹ̀ tí kó ní òsùnwọ̀n nínú àwa tí ó gbàgbọ́ gẹ́gẹ́bí síse isẹ́ títóbi nípa okun Rẹ̀. \v 20 Èyí ni òduwọ̀n agbára kannà tí Ọlọ́run fi sisẹ́ nínú Krístì, nígbàtí Ó jíi dide ninu awon oku ti o si mu ki o joko ni owo otun Re ninu awon orun. \v 21 O mu ki Krisiti joko rekoja gbogbo isakoso ati ase ati agbara, ati ijoba ati oruko ko ruko ti a le da. Kristi yoo se akoso, kii se ni aye yii nikan sugbon, koda ni aye ti mbo pelu. \ No newline at end of file +\v 19 Nínú àdúrà mi, mo béèrè wípé kí ẹ̀yin kí ó lè mọ títóbi agbára Rẹ̀ tí kó ní òsùnwọ̀n nínú àwa tí ó gbàgbọ́ gẹ́gẹ́bí síse isẹ́ títóbi nípa okun Rẹ̀. \v 20 Èyí ni òduwọ̀n agbára kannà tí Ọlọ́run fi sisẹ́ nínú Krístì, nígbàtí Ó jíi dìde nínú àwọn òkú tí ó sì mú kí ó jòkó ní ọwọ́ ọ̀tún Re ninu awon orun. \v 21 O mu ki Krisiti joko rekoja gbogbo isakoso ati ase ati agbara, ati ijoba ati oruko ko ruko ti a le da. Kristi yoo se akoso, kii se ni aye yii nikan sugbon, koda ni aye ti mbo pelu. \ No newline at end of file