Fri Jul 12 2019 11:08:36 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
20e12a0797
commit
a5087d8a6e
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 19 Nítorínáà nísinsìnyí, ẹ̀yin Kèfèrí kìí se àlejò àti àjèjì mọ dipo bẹ́ẹ̀ ẹ ti di ọmọ ìbílẹ̀ kanna pẹ̀lú àwọn ènìyàn mímọ àti ọmọ agbo ile Ọlọ́run. \v 20 A ti kó yin lé orí ìpìlẹ̀ àwọn Aposteli àti àwọn wóòli, ati Kristi Jesu funrarẹ si ni okuta igun ilé. \v 21 Nínú Rẹ gbogbo ilé ẹ di ara won papo, o si n dagba gẹgẹbi Tempili ninu Oluwa. \v 22 Nínú Rẹ̀ ni a ti ń kó ẹ̀yín pẹ̀lú papo gẹ́gẹ́bí ibùgbé fún Ọlọrun nínú Ẹ̀mí.
|
||||
\v 19 Nítorínáà nísinsìnyí, ẹ̀yin Kèfèrí kìí se àlejò àti àjèjì mọ dipo bẹ́ẹ̀ ẹ ti di ọmọ ìbílẹ̀ kanna pẹ̀lú àwọn ènìyàn mímọ àti ọmọ agbo ile Ọlọ́run. \v 20 A ti kó yin lé orí ìpìlẹ̀ àwọn Aposteli àti àwọn wóòli, ati Kristi Jesu funrarẹ si ni okuta igun ilé. \v 21 Nínú Rẹ gbogbo ilé ẹ di ara won papo, o si n dagba gẹ́gẹ́bí Tempili ninu Oluwa. \v 22 Nínú Rẹ̀ ni a ti ń kó ẹ̀yín pẹ̀lú papo gẹ́gẹ́bí ibùgbé fún Ọlọrun nínú Ẹ̀mí.
|
Loading…
Reference in New Issue