diff --git a/02/19.txt b/02/19.txt index 7a97493..1e2cee6 100644 --- a/02/19.txt +++ b/02/19.txt @@ -1 +1 @@ -\v 19 Nítorínáà nísinsìnyí, ẹ̀yin Kèfèrí kìí se àlejò àti àjèjì mọ dipo bẹ́ẹ̀ ẹ ti di ọmọ ìbílẹ̀ kanna pẹ̀lú àwọn ènìyàn mímọ àti ọmọ agbo ile Ọlọ́run. \v 20 A ti kó yin lé orí ìpìlẹ̀ àwọn Aposteli àti àwọn wóòli, ati Kristi Jesu funrarẹ si ni okuta igun ilé. \v 21 Nínú Rẹ gbogbo ilé ẹ di ara won papo, o si n dagba gẹgẹbi Tempili ninu Oluwa. \v 22 Nínú Rẹ̀ ni a ti ń kó ẹ̀yín pẹ̀lú papo gẹ́gẹ́bí ibùgbé fún Ọlọrun nínú Ẹ̀mí. \ No newline at end of file +\v 19 Nítorínáà nísinsìnyí, ẹ̀yin Kèfèrí kìí se àlejò àti àjèjì mọ dipo bẹ́ẹ̀ ẹ ti di ọmọ ìbílẹ̀ kanna pẹ̀lú àwọn ènìyàn mímọ àti ọmọ agbo ile Ọlọ́run. \v 20 A ti kó yin lé orí ìpìlẹ̀ àwọn Aposteli àti àwọn wóòli, ati Kristi Jesu funrarẹ si ni okuta igun ilé. \v 21 Nínú Rẹ gbogbo ilé ẹ di ara won papo, o si n dagba gẹ́gẹ́bí Tempili ninu Oluwa. \v 22 Nínú Rẹ̀ ni a ti ń kó ẹ̀yín pẹ̀lú papo gẹ́gẹ́bí ibùgbé fún Ọlọrun nínú Ẹ̀mí. \ No newline at end of file