Sat Aug 03 2019 02:26:41 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-08-03 02:26:44 +01:00
parent 2eddbc1c4b
commit 8da0a3f370
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 18 Ẹ má sì se fi ara yín fún ọtí mímu, nítorí èyí á mú kí ènìyàn si ìwà hù, sùgbọ́n ẹ kúkú máa kún fún Ẹ̀mímímọ́. \v 19 Kí ẹ má bá ara yín sọ̀rọ̀ pẹ̀lú orin Psáàlmù àti àwọn orin, àti orin ẹ̀mi, kí ẹ máa kọ́ orin ninu ẹmi si Oluwa lati inu ọkan yin wa. \v 20 Ẹ maa dupẹ fun ohun gbogbo ni orukọ Oluwa wa Jesu Kristi si Ọlọrun Baba náà. \v 21 Ẹ maa tẹriba fun ara yin pẹlu ọwọ fun Kristi.
\v 18 Ẹ má sì se fi ara yín fún ọtí mímu, nítorí èyí á mú kí ènìyàn si ìwà hù, sùgbọ́n ẹ kúkú máa kún fún Ẹ̀mímímọ́. \v 19 Kí ẹ má bá ara yín sọ̀rọ̀ pẹ̀lú orin Psáàlmù àti àwọn orin, àti orin ẹ̀mi, kí ẹ máa kọ́ orin nínú ẹ̀mí sí Olúwa láti inú ọkàn yín wá. \v 20 Ẹ máa dúpẹ́ fún ohun gbogbo ní orúkọ Olúwa wa Jésù Krístì sí Ọlọrun Baba náà. \v 21 Ẹ maa tẹriba fun ara yin pẹlu ọwọ fun Kristi.