From 8da0a3f37058493d5e1fe5a0da33ded1f27e2445 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: tsDesktop Date: Sat, 3 Aug 2019 02:26:44 +0100 Subject: [PATCH] Sat Aug 03 2019 02:26:41 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 05/18.txt | 2 +- 1 file changed, 1 insertion(+), 1 deletion(-) diff --git a/05/18.txt b/05/18.txt index e0fdb8a..5e41ed4 100644 --- a/05/18.txt +++ b/05/18.txt @@ -1 +1 @@ -\v 18 Ẹ má sì se fi ara yín fún ọtí mímu, nítorí èyí á mú kí ènìyàn si ìwà hù, sùgbọ́n ẹ kúkú máa kún fún Ẹ̀mímímọ́. \v 19 Kí ẹ má bá ara yín sọ̀rọ̀ pẹ̀lú orin Psáàlmù àti àwọn orin, àti orin ẹ̀mi, kí ẹ máa kọ́ orin ninu ẹmi si Oluwa lati inu ọkan yin wa. \v 20 Ẹ maa dupẹ fun ohun gbogbo ni orukọ Oluwa wa Jesu Kristi si Ọlọrun Baba náà. \v 21 Ẹ maa tẹriba fun ara yin pẹlu ọwọ fun Kristi. \ No newline at end of file +\v 18 Ẹ má sì se fi ara yín fún ọtí mímu, nítorí èyí á mú kí ènìyàn si ìwà hù, sùgbọ́n ẹ kúkú máa kún fún Ẹ̀mímímọ́. \v 19 Kí ẹ má bá ara yín sọ̀rọ̀ pẹ̀lú orin Psáàlmù àti àwọn orin, àti orin ẹ̀mi, kí ẹ máa kọ́ orin nínú ẹ̀mí sí Olúwa láti inú ọkàn yín wá. \v 20 Ẹ máa dúpẹ́ fún ohun gbogbo ní orúkọ Olúwa wa Jésù Krístì sí Ọlọrun Baba náà. \v 21 Ẹ maa tẹriba fun ara yin pẹlu ọwọ fun Kristi. \ No newline at end of file