Sat Aug 03 2019 09:05:55 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-08-03 09:05:57 +01:00
parent 3a01ae9bf2
commit 25c34b317c
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 5 Ẹ̀yin ọmọ ọ̀dọ̀, ẹ gbọ́ràn sí àwọn ọ̀gá yín nínú ayé pẹ̀lú ọ̀wọ̀ tí jinlẹ̀ àti ìwárìrì, nínú òtítọ́ ọkàn yín, Ẹ gbọ́ràn sí won bí ẹ ó se gbọ́ràn sí Krístì. \v 6 .Ẹ gbọ́ràn, kìí se nígbàtí ọ̀gá ń wò yín, kí ẹ ba leè mú inú wọn dùn, bíkòse pé kí ẹ gbọ́ràn bí ọmọ ọ̀dọ̀ Krístì, tí ó ń se ìfẹ́ Ọlọ́run láti inú ọkàn rẹ̀. \v 7 Ẹ se isẹ́ yín pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín, gẹ́gẹ́bí ẹnití ń sisẹ́ fún Olúwa tí kìí sì se ènìyàn. \v 8 Nítorí àwa mọ̀ pé ohun rere kóhun rere tí ẹnikọọkan ba se, yoo gba ere lọwọ Oluwa, iba se ẹru tabi ominira.
\v 5 Ẹ̀yin ọmọ ọ̀dọ̀, ẹ gbọ́ràn sí àwọn ọ̀gá yín nínú ayé pẹ̀lú ọ̀wọ̀ tí jinlẹ̀ àti ìwárìrì, nínú òtítọ́ ọkàn yín, Ẹ gbọ́ràn sí won bí ẹ ó se gbọ́ràn sí Krístì. \v 6 .Ẹ gbọ́ràn, kìí se nígbàtí ọ̀gá ń wò yín, kí ẹ ba leè mú inú wọn dùn, bíkòse pé kí ẹ gbọ́ràn bí ọmọ ọ̀dọ̀ Krístì, tí ó ń se ìfẹ́ Ọlọ́run láti inú ọkàn rẹ̀. \v 7 Ẹ se isẹ́ yín pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín, gẹ́gẹ́bí ẹnití ń sisẹ́ fún Olúwa tí kìí sì se ènìyàn. \v 8 Nítorí àwa mọ̀ pé ohun rere kóhun rere tí ẹnìkọ̀ọ̀kan bá se, yóò gbà èrè lwọ Oluwa, iba se ẹru tabi ominira.