diff --git a/06/05.txt b/06/05.txt index b0d6056..1f84de3 100644 --- a/06/05.txt +++ b/06/05.txt @@ -1 +1 @@ -\v 5 Ẹ̀yin ọmọ ọ̀dọ̀, ẹ gbọ́ràn sí àwọn ọ̀gá yín nínú ayé pẹ̀lú ọ̀wọ̀ tí jinlẹ̀ àti ìwárìrì, nínú òtítọ́ ọkàn yín, Ẹ gbọ́ràn sí won bí ẹ ó se gbọ́ràn sí Krístì. \v 6 .Ẹ gbọ́ràn, kìí se nígbàtí ọ̀gá ń wò yín, kí ẹ ba leè mú inú wọn dùn, bíkòse pé kí ẹ gbọ́ràn bí ọmọ ọ̀dọ̀ Krístì, tí ó ń se ìfẹ́ Ọlọ́run láti inú ọkàn rẹ̀. \v 7 Ẹ se isẹ́ yín pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín, gẹ́gẹ́bí ẹnití ń sisẹ́ fún Olúwa tí kìí sì se ènìyàn. \v 8 Nítorí àwa mọ̀ pé ohun rere kóhun rere tí ẹnikọọkan ba se, yoo gba ere lọwọ Oluwa, iba se ẹru tabi ominira. \ No newline at end of file +\v 5 Ẹ̀yin ọmọ ọ̀dọ̀, ẹ gbọ́ràn sí àwọn ọ̀gá yín nínú ayé pẹ̀lú ọ̀wọ̀ tí jinlẹ̀ àti ìwárìrì, nínú òtítọ́ ọkàn yín, Ẹ gbọ́ràn sí won bí ẹ ó se gbọ́ràn sí Krístì. \v 6 .Ẹ gbọ́ràn, kìí se nígbàtí ọ̀gá ń wò yín, kí ẹ ba leè mú inú wọn dùn, bíkòse pé kí ẹ gbọ́ràn bí ọmọ ọ̀dọ̀ Krístì, tí ó ń se ìfẹ́ Ọlọ́run láti inú ọkàn rẹ̀. \v 7 Ẹ se isẹ́ yín pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín, gẹ́gẹ́bí ẹnití ń sisẹ́ fún Olúwa tí kìí sì se ènìyàn. \v 8 Nítorí àwa mọ̀ pé ohun rere kóhun rere tí ẹnìkọ̀ọ̀kan bá se, yóò gbà èrè lwọ Oluwa, iba se ẹru tabi ominira. \ No newline at end of file