Thu Jun 27 2019 22:17:51 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 22:17:52 +01:00
parent 2dad53f708
commit 16491d50e0
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 8 Nítorí nípa ore ọ̀fẹ́ ni a ti fi gbà yín là, nípa ìgbàgbọ́, èyí kò sì ti ọ̀dọ̀ yín wá, ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run ni. \v 9 Ore ọfẹ́ kò ti ipa isẹ́ wá nítorináà ẹnìkan kò leè sògo. \v 10 Nítorí isẹ́ ọwọ́ Rẹ̀ ni wá, tí a dá nínú Krístì Jésù láti se isẹ́ rere tí Ọlọ́run se èètò fún láti ọjọ́ tó ti pẹ́ fún wa, kí àwa ki o le rin ninu won.
\v 8 Nítorí nípa ore ọ̀fẹ́ ni a ti fi gbà yín là, nípa ìgbàgbọ́, èyí kò sì ti ọ̀dọ̀ yín wá, ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run ni. \v 9 Ore ọfẹ́ kò ti ipa isẹ́ wá nítorináà ẹnìkan kò leè sògo. \v 10 Nítorí isẹ́ ọwọ́ Rẹ̀ ni wá, tí a dá nínú Krístì Jésù láti se isẹ́ rere tí Ọlọ́run se èètò fún láti ọjọ́ tó ti pẹ́ fún wa, kí àwa kí ó lè rìn nínú won.

View File

@ -1 +1 @@
\v 11 Nitorinaa e ranti wipe nigakan ri, e je keferi ninu ara. A pe yin ni "alaikola" nipa ohun ti a pe ni "ikola" ninu ara ti a se nipa owo eniyan. \v 12 Ni igbana e wa ni iyapa pelu Kristi. E je alejo si awon ara Isreli. E je alejo si majemu naa ti a ti se ileri. E ko ni ireti kan fun ojo ola, E si wa laini Olorun ninu aye.
\v 11 Nítorínaáà ẹ rántí wípé nigakan ri, e je keferi ninu ara. A pe yin ni "alaikola" nipa ohun ti a pe ni "ikola" ninu ara ti a se nipa owo eniyan. \v 12 Ni igbana e wa ni iyapa pelu Kristi. E je alejo si awon ara Isreli. E je alejo si majemu naa ti a ti se ileri. E ko ni ireti kan fun ojo ola, E si wa laini Olorun ninu aye.