diff --git a/02/08.txt b/02/08.txt index 898c0ec..505a768 100644 --- a/02/08.txt +++ b/02/08.txt @@ -1 +1 @@ -\v 8 Nítorí nípa ore ọ̀fẹ́ ni a ti fi gbà yín là, nípa ìgbàgbọ́, èyí kò sì ti ọ̀dọ̀ yín wá, ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run ni. \v 9 Ore ọfẹ́ kò ti ipa isẹ́ wá nítorináà ẹnìkan kò leè sògo. \v 10 Nítorí isẹ́ ọwọ́ Rẹ̀ ni wá, tí a dá nínú Krístì Jésù láti se isẹ́ rere tí Ọlọ́run se èètò fún láti ọjọ́ tó ti pẹ́ fún wa, kí àwa ki o le rin ninu won. \ No newline at end of file +\v 8 Nítorí nípa ore ọ̀fẹ́ ni a ti fi gbà yín là, nípa ìgbàgbọ́, èyí kò sì ti ọ̀dọ̀ yín wá, ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run ni. \v 9 Ore ọfẹ́ kò ti ipa isẹ́ wá nítorináà ẹnìkan kò leè sògo. \v 10 Nítorí isẹ́ ọwọ́ Rẹ̀ ni wá, tí a dá nínú Krístì Jésù láti se isẹ́ rere tí Ọlọ́run se èètò fún láti ọjọ́ tó ti pẹ́ fún wa, kí àwa kí ó lè rìn nínú won. \ No newline at end of file diff --git a/02/11.txt b/02/11.txt index f7d2459..d9c3510 100644 --- a/02/11.txt +++ b/02/11.txt @@ -1 +1 @@ -\v 11 Nitorinaa e ranti wipe nigakan ri, e je keferi ninu ara. A pe yin ni "alaikola" nipa ohun ti a pe ni "ikola" ninu ara ti a se nipa owo eniyan. \v 12 Ni igbana e wa ni iyapa pelu Kristi. E je alejo si awon ara Isreli. E je alejo si majemu naa ti a ti se ileri. E ko ni ireti kan fun ojo ola, E si wa laini Olorun ninu aye. \ No newline at end of file +\v 11 Nítorínaáà ẹ rántí wípé nigakan ri, e je keferi ninu ara. A pe yin ni "alaikola" nipa ohun ti a pe ni "ikola" ninu ara ti a se nipa owo eniyan. \v 12 Ni igbana e wa ni iyapa pelu Kristi. E je alejo si awon ara Isreli. E je alejo si majemu naa ti a ti se ileri. E ko ni ireti kan fun ojo ola, E si wa laini Olorun ninu aye. \ No newline at end of file