Thu May 27 2021 14:08:37 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2021-05-27 14:08:42 +01:00
parent 6850c3af10
commit 0b5ea9e73a
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 18 Ẹ̀yin ìyàwó, ẹ tẹríba fún àwọn ọkọ yín, gẹ́gẹ́bí ó ti tọ́ nínú Olúwa. \v 19 Ẹ̀yin ọkọ, ẹ fẹ́ran àwọn ìyàwó yín, àti pé kí ẹ má se kurò sí wọn. \v 20 Ẹ̀yin ọmọ, ẹ máa gbọ́ràn si àwọn òbí yín lẹ́nu nínú ohun gbogbo, nítorí eyí ní o dára nínú Olúwa. \v 21 Ẹ̀yin bàbá, ẹ má se máa mu àwọn ọmọ yín bínú, kí wọn má bá rẹ̀wẹ̀sì.
\v 18 Ẹ̀yin ìyàwó, ẹ tẹríba fún àwọn ọkọ yín, gẹ́gẹ́bí ó ti tọ́ nínú Olúwa. \v 19 Ẹ̀yin ọkọ, ẹ fẹ́ran àwọn ìyàwó yín, àti pé kí ẹ má se korò sí wọn. \v 20 Ẹ̀yin ọmọ, ẹ máa gbọ́ràn si àwọn òbí yín lẹ́nu nínú ohun gbogbo, nítorí eyí ní o dára nínú Olúwa. \v 21 Ẹ̀yin bàbá, ẹ má se máa mu àwọn ọmọ yín bínú, kí wọn má bá rẹ̀wẹ̀sì.