Thu May 27 2021 14:06:37 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
051c1a22b9
commit
6850c3af10
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 15 Ẹ jẹ́ ki àlàfíà Kristi jọba ni ọkàn yín. Nítorí ti àlàfíà yíí ni a se pè yín sínú ara kan. Àti p ki ẹ máa kún fún ìdúpẹ́. \v 16 Ẹ jẹ́ ki ọ̀rọ Kristi máa gbe inú yín lọ́pọ̀lọpọ̀. Ẹ máa kọ́ ní pẹ̀lú ọgbọ́n gbogbo bẹ́èní ẹ máa rọ olúkúlùkù pẹ̀lu àwọn Sáàmù àti àwọn orin iyin àti àwọn orin ẹ̀mí. Ẹ kọrin pẹ̀lu ẹ̀kùnrẹ́rẹ́ ọpẹ́ ní ọkàn yín fún Ọlọrun \v 17 Ohunkóhun ti ẹ̀yín bá nse, nínú ọ̀rọ̀ sísọ tàbí nínú ìṣe, ẹ ṣe gbogbo rẹ̀ ní orúkọ Jésù Olúwa. Kí ẹ si máa fi ọpẹ́ fún Ọlọrun Baba nípasẹ̀ rẹ̀.
|
||||
\v 15 Ẹ jẹ́ ki àlàfíà Kristi jọba ni ọkàn yín. Nítorí ti àlàfíà yíí ni a se pè yín sínú ara kan. Àti pé ki ẹ máa kún fún ìdúpẹ́. \v 16 Ẹ jẹ́ ki ọ̀rọ Kristi máa gbe inú yín lọ́pọ̀lọpọ̀. Ẹ máa kọ́ ní pẹ̀lú ọgbọ́n gbogbo bẹ́èní ẹ máa rọ olúkúlùkù pẹ̀lu àwọn Sáàmù àti àwọn orin iyin àti àwọn orin ẹ̀mí. Ẹ kọrin pẹ̀lu ẹ̀kùnrẹ́rẹ́ ọpẹ́ ní ọkàn yín fún Ọlọrun \v 17 Ohunkóhun ti ẹ̀yín bá nse, nínú ọ̀rọ̀ sísọ tàbí nínú ìṣe, ẹ ṣe gbogbo rẹ̀ ní orúkọ Jésù Olúwa. Kí ẹ si máa fi ọpẹ́ fún Ọlọrun Baba nípasẹ̀ rẹ̀.
|
Loading…
Reference in New Issue