Mon Jun 14 2021 19:21:48 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2021-06-14 19:21:49 +01:00
parent e6f4e3fb22
commit 0546850f9d
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 10 A sì ti sọ yín di kíkún nínú Rẹ̀, ẹnití ó jẹ̀ orí lórí gbogbo ipá àti agbára. \v 11 Nínú Rẹ̀ ni a sì kọ ẹ̀yin náà n'ílà pẹ̀lú, ìkọlà tí a kò ti ọwọ́ ènìyàn ṣe níti mímú ẹran ara kúrò, ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí ìkọlà Krístì. \v 12 A ti sin yín pẹ̀lú Rẹ̀ nínú ìrìbọmi, àti nínú Rẹ̀ ni a jí yín dìde nípa ìgbàgbọ́ nínú agbára Ọlọrun, enití o jí Kristi dìde nínú òkú.
\v 10 A sì ti sọ yín di kíkún nínú Rẹ̀, ẹnití ó jẹ̀ orí lórí gbogbo ipá àti agbára. \v 11 Nínú Rẹ̀ ni a sì kọ ẹ̀yin náà n'ílà pẹ̀lú, ìkọlà tí a kò ti ọwọ́ ènìyàn ṣe níti mímú ẹran ara kúrò, ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí ìkọlà Krístì. \v 12 A ti sin yín pẹ̀lú Rẹ̀ nínú ìrìbọmi, àti nínú Rẹ̀ ni a jí yín dìde nípa ìgbàgbọ́ nínú agbára Ọlọ́run, enití ó jí Krístì dìde nínú òkú.

View File

@ -1 +1 @@
\v 13 nígbàti ẹ̀yín jẹ́ òkú nínú àwon ẹ̀ṣẹ yín àtí nínú ìkọlà ẹran ara, Òn sọ yín di àyé pẹ̀lú ara rẹ̀ bẹ́ẹ̀ni ó dári àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín jìyín. \v 14 Ó fagilé àkọsílẹ̀ gbogbo gbése ẹ̀ṣẹ̀ tí ó dúró lòdì sí wa ti on ti ìlàna rẹ̀. Ó mú kúro nípa kíkán mọ àgbélèbú. \v 15 Ó gba ipá lọ́wọ́ àwọn agbárá atí aláàṣẹ́, béní o se àfihan wón ni gbángba, nítipé o ṣẹ́gun wọ́n lori àgbelèbú.
\v 13 Nígbàtí ẹ̀yín jẹ́ òkú nínú àwon ẹ̀ṣẹ yín àti nínú ìkọlà ẹran ara, Òun sọ yín di ààyé pẹ̀lú ara rẹ̀ bẹ́ẹ̀ni ó dári àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín jìyín. \v 14 Ó fagilé àkọsílẹ̀ gbogbo gbése ẹ̀ṣẹ̀ tí ó dúró lòdì sí wa ti on ti ìlàna rẹ̀. Ó mú kúro nípa kíkán mọ àgbélèbú. \v 15 Ó gba ipá lọ́wọ́ àwọn agbárá atí aláàṣẹ́, béní o se àfihan wón ni gbángba, nítipé o ṣẹ́gun wọ́n lori àgbelèbú.

View File

@ -54,7 +54,7 @@
"02-04",
"02-06",
"02-08",
"02-13",
"02-10",
"02-16",
"02-18",
"02-20",