Mon Jun 14 2021 19:19:48 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2021-06-14 19:19:49 +01:00
parent 78f649b7c8
commit e6f4e3fb22
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 10 A sì ti sọ yín di kíkún nínú Rẹ̀, ẹnití ó jẹ̀ orí lórí gbogbo ipá àti agbára. \v 11 Nínú Rẹ̀ ni a sì kọ ẹ̀yin náà n'ílà pẹ̀lú, ìkọlà tí a kò ti ọwọ́ ènìyàn ṣe níti mímú abala ẹran ara kúrò, sugbọ̀n gẹ́gẹ́bí ikọlà Kristi. \v 12 A ti sin yín pẹ̀lu Rẹ̀ nínú baptismu, àti nínú Rẹ̀ ni a jí yín dìde nipa ìgbàgbọ́ nínú agbára Ọlọrun, enití o jí Kristi dìde nínú òkú.
\v 10 A sì ti sọ yín di kíkún nínú Rẹ̀, ẹnití ó jẹ̀ orí lórí gbogbo ipá àti agbára. \v 11 Nínú Rẹ̀ ni a sì kọ ẹ̀yin náà n'ílà pẹ̀lú, ìkọlà tí a kò ti ọwọ́ ènìyàn ṣe níti mímú ẹran ara kúrò, ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí ìkọlà Krístì. \v 12 A ti sin yín pẹ̀lú Rẹ̀ nínú ìrìbọmi, àti nínú Rẹ̀ ni a jí yín dìde nípa ìgbàgbọ́ nínú agbára Ọlọrun, enití o jí Kristi dìde nínú òkú.