Thu Jan 14 2021 16:29:46 GMT-0500 (EST)

This commit is contained in:
scunningham 2021-01-14 16:29:46 -05:00
commit 8c6f3728de
8 changed files with 55 additions and 0 deletions

1
01/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\c 1 \v 1 Alàgbà náà sí Gáíù olùfẹ́, ẹnití mo fẹ́ràn ní òtítọ́. \v 2 Olùfẹ́, mo gbàdúrà pé kí o le ṣe rere nínú ohun gbogbo àti kí o sì wà ní ìlera, gẹ́gẹ́ bí ọkàn rẹ se ń ṣe rere. \v 3 Nítorí mo yọ ayọ̀ ńláńlá nígbàtí àwọn arákùnrin dé tí wọ́n sì j'ẹ̀rí sí òtítọ́ rẹ, gẹ́gẹ́ bí o ti fi òtítọ́ rìn. \v 4 Èmi kò ní ayọ̀ ńlá kan tí óju báyìí lọ, láti gbọ́ pé àwọn ọmọ mi ń rìn nínú òtítọ́.

1
01/05.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 5 Olùfẹ́, ìwọ ń fi ìsòtítọ́ sí ìse ní gbogbo ìgbà tí o báse isẹ́ fún àwọn arákùnrin àti fún àwọn àlejò, \v 6 àwọn tí wọ́n ti jẹ́rìí sí ìfẹ́ rẹ níiwájú ìjọ. Ìwọ se dáradára tí o sìn wọ́n sọ́nà ni ọ̀nà tí ó yẹ sí Ọlọ́run, \v 7 nítorípé nítorí ti orúkọ Olúwa ni wọ́n jáde lọ, láí gba ohunkóhun lọ́wọ́ àwọn kèfèrí. \v 8 Nítorínà a gbọdọ̀ fi ààye gba irú àwọn ènìyàn báwọ̀nyí, a ó sìle jọ jẹ́ alábàásisẹ́pọ̀ fún òtítọ́.

1
01/09.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 9 Mo kọ ìwé sí agbo náà, ṣùgbọ́n Díótréfìs, ẹnití ó fẹ́ láti máa jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ láàrin wọn, kò fi àyè gbà wá. \v 10 Nítorínà, bí mo bá dé, èmi ó mú ìṣe rẹ̀ tí ó ń ṣe wá sí ìrántí, bí ó se ń sọ àwọn ọ̀rọ̀ búburú ní ìlòdì sí wa láti yẹ̀yẹ́ wa. Àwọn ìṣe wọ̀nyí kò sì tún tó o, òun tìkalárarẹ̀ kò tùn fi ààyè gba àwọn arákùnrin náà. Ó ń dá àwọn tí wọ́n fẹ́ se lẹ́kun, ó sì tún ń lé wọn jáde kúrò nínù agbo.

1
01/11.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 11 Olufẹ́, máse se àfarawé ohun tí íse ibi ṣùgbọ́n ohun tí ń se rere. Ẹnití ó se rere jẹ́ ti Ọlọ́run; ẹni tí ó ń ṣe ibi kò tí rí Ọlọ́run. \v 12 Òtítọ́ jẹ́rìí gbe Démétíríù àti àwọn ènìyàn jẹ́ríì rẹ̀. Àwa pẹ̀lú se ẹlẹ́rìí, ẹ sì mọ̀ pé ẹ̀rí wa òtítọ́ ni.

1
01/13.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 13 Mo ní ohun púpọ̀ láti kọ síi yín, ṣùgbọ́n n kò fẹ́ kọ wọ́n pèlúu kálàmù àti aró. \v 14 Ṣùgbọ́n mo ní ìrètí láti rí yín láìpẹ́, a ó sì sọ̀rọ̀ lójúkoojú. \v 15 Kí àlàáfíà wà pẹ̀lú yín. Àwọn ọ̀rẹ́ kìi yín. Ẹ kí àwọn ọ̀rẹ́ ní pẹ̀lú orúkọ ẹnìkọ̀ọ̀kan.

1
01/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Orí Kinni

1
front/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
3 John

48
manifest.json Normal file
View File

@ -0,0 +1,48 @@
{
"package_version": 6,
"format": "usfm",
"generator": {
"name": "ts-desktop",
"build": "5"
},
"target_language": {
"id": "yo",
"name": "Yorùbá",
"direction": "ltr"
},
"project": {
"id": "3jn",
"name": "3 John"
},
"type": {
"id": "text",
"name": "Text"
},
"resource": {
"id": "ulb",
"name": "Unlocked Literal Bible"
},
"source_translations": [
{
"language_id": "en",
"resource_id": "ulb",
"checking_level": "3",
"date_modified": "2017-11-29T00:00:00+00:00",
"version": "12"
}
],
"parent_draft": {},
"translators": [
"ALAMU, ESTHER OYELOLA",
"Steven Cunningham"
],
"finished_chunks": [
"front-title",
"01-title",
"01-01",
"01-05",
"01-09",
"01-11",
"01-13"
]
}