Tue May 11 2021 11:40:33 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
iconcept 2021-05-11 11:40:34 +01:00
commit 8582a39dbb
38 changed files with 84 additions and 2 deletions

3
03/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,3 @@
\c 3 \v 1 Ọ̀rọ̀ yí gbọdọ̀ jẹ̀ òtítọ́: Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ láti jẹ́ alámòjútó, oun fẹ́ isẹ́ rere.
\v 2 Nítorínà alámòjútó gbọdọ̀ wà láì lẹ́bi. Ó gbọdọ̀ jẹ̀ ọkọ aláya kan. Ó gbọdọ̀ jẹ̀ oníwọ̀ntunwọ̀nsì, olórí pípé, omolúàbí, ẹni tí ń se àlejò. Ó gbọdọ̀ leè kọ́ ni.
\v 3 Kò gbọdọ̀ jẹ̀ ọ̀mùtí para, oníjà, ṣùgbọ́n kí ó jẹ́ oníwà pẹ̀lẹ́ àti alálàáfíà. Kò gbọdọ̀ jẹ́ ẹni tó fẹ́ràn owó.

1
03/04.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 4 Ó gbọdọ̀ bójútó inú ile rẹ̀ dáradára, àwọn ọmọ rẹ̀ sì gbọdọ̀ gbọ́ràn sìi lẹ̀nu pẹ̀lú gbogbo ọ̀wọ̀. \v 5 Nítorí tí arákùnrin kan kò bá le è mójútó ilé ara rẹ̀, báwo ni yóò ṣe mójútó ilé Ọlọ́run?

2
03/06.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,2 @@
\v 6 Kò gbọdọ̀ jẹ́ onígbàgbọ́ titun, kí ó má baà gbéraga. Kí ó sì subú sínú ìdálẹ́bi bíi èsù.
\v 7 Ó gbọdọ̀ ní ẹ̀rí tí ó dára pẹ̀lú ará àdúgbò, kí ó má baà bọ́ sínú ìtìjú àti pańpẹ́ èsù.

2
03/08.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,2 @@
\v 8 Àwọn díákónì, pẹ̀lú gbọdọ̀ lọ́lá, kìí se ẹlẹ́nu méjì. Wọn kò gbọdọ̀ jẹ́ ọ̀mùtí para tàbí olójú kòkòrò.
\v 9 Wọ́n gbọdọ̀ pa òtítọ́ ìgbàgbọ́ tí a fi hàn mọ́ pẹ̀lú ẹ̀rí ọkàn tó mọ́. \v 10 Wọ́n gbọdọ̀ kọ́kọ́ di ẹni ìtẹ́wọ́gbà, nígbànáà wọ́n gbọdọ́ ṣe isẹ́ ìránṣẹ́ nítorí wọn kò lẹ́bi.

1
03/11.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 11 Àwọn obìnrin lọ́nà kan náà gbọdọ̀ lọ́lá. Wọn kò gbọdọ̀ jẹ́ asọ̀rọ̀ òdì. Wọ́n gbọdọ̀ jẹ̀ oníwọ̀ntunwọ̀nsì àti olóòtọ́ ní gbogbo ọ̀nà. \v 12 Àwọn díákónì gbọdọ̀ jẹ́ ọkọ oní ìyàwó kan. Wọ́n gbọdọ̀ le ṣe àmójútó àwọn ọmọ wọn àti ilé wọn dáradára. \v 13 Nítorí àwọn tì ó ti sìn dáradára gba orúkọ rere àti ìgboyà ńlá nínú ìgbàgbọ́ tí ó wà nínú Krístì Jésù.

1
03/14.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 14 Èmi ń kọ àwọn nǹkan wọ̀nyí sí ọ, mo sì ní ìrètí láti tọ̀ ọ́ wá láìpẹ́. \v 15 Ṣùgbọ́n tí ó bá pẹ́ mi, èmi ń kọ̀wé kí o ba le mọọ bí a ti ń wùwà láàrín àwọn ènìyàn Ọlọ́run, tíí ṣe ìjọ Ọlọ́run alààyè, òpó àti àtìlẹ́yìn òtítọ́.

1
03/16.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 16 Kò sí ẹnikẹ́ni tí ó le jiyàn wípé ìjìnlẹ̀ ńlá ni òtítọ́ ti Ọlọ́run ii hàn. " Ó fara hàn nínú ẹran ara, ó gba ìdáláre nípa Ẹ̀mí, àwọn ángẹ́lì rí i, wọ́n kéde Rẹ̀ láàrín àwọn orílẹ̀ èdè, asì gbà á sókè nínú ògo.

1
03/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Orí Kẹta

1
04/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\c 4 \v 1 Nísinsìnyí Ẹ̀mí ń ké tantan wípé ní ìgbà ìkẹyìn àwọn ènìyàn kan yóó fi ìgbàgbọ́ sílẹ̀, wọ́n yóò sì fi iyè sí àwọn ẹni ẹ̀tàn àti ìkọ́ni àwọn démónì. \v 2 Nínú àgàbàgebè irò. Ẹ̀rí ọkàn wọn yóó di ti sàtánì.

1
04/03.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 5 \v 3 Wọ́n ó kọ̀ láti ṣe ìgbéyàwó àti láti gba óúnjẹ ti Ọlọ́run dá fún pínpín pẹ̀lú ọpẹ́ láàrín àwọn tí ó gbàgbọ́ tí ó sì mọ òtítọ́. \v 4 Nítorí gbogbo oun tí Ọlọ́run dá dáradára ni. kò sí oun tí a gbà pẹ̀ú ọpẹ́ tí ó gbọdọ̀ di kíkọ̀.\v 5 Nítorí ati yàá sí mímọ́ pẹ̀lú ọ̀rọ̀ Ọlọ́run àti àdúrà.

1
04/06.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 6 Ìwọ yóó jẹ́ ìránṣẹ́ Jésù Kristì tí ó dára tí ìwọ bá gbé gbogbo àwọn ǹkan wọ̀nyí síwaju àwọn ará. Nítorí à ńbọ́ ọ pẹ̀lú àwọn òrò ìgbàgbọ́ àti pẹ̀lú ìkọ́ni tí ó yè koro tí ó ti tẹ̀lé. \v 7 Ṣùgbọ́n kọ gbògbo àwọn àlọ́ àti ìtàn tí kò wúlò. Nípò rẹ̀, kọ́ arà rẹ ní ìwà bí Ọlọ́run. \v 8 Ìwúlò eré ìdárayá díè ni, ṣùgbọ́n ìwà bíi Ọlọ́run wúlò fún ohun gbogbo. Óní èrè fún ayé yìí nísinsìnyí àti fún ayé èyí tó ńbọ̀.

1
04/09.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 9 Òdodo ni ọ̀rọ̀ yí, ó sì yẹ fùn ìtẹ́wọ́gbà tokàntokàn. \v 10 Nítorí fún èyí ni àwa sì ń ṣiṣẹ́ kárakára. Nítorí àwa ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Ọlọ́run alààyè, eni tí ń ṣe Olùgbàlà gbogbo ènìyan, pàápáà jùlọ àwọn onígbàgbọ́.

1
04/11.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 11 Máa kéde kí o sì máà kọ́ àwọn ǹkan wọnyi. \v 12 Má ṣe jé kí ẹnikọ́ni gan jíjẹ́ ọ̀dọ́ rẹ. Dípò, jẹ́ àpẹ̀ẹrẹ fún àwọn tí ó gbàgbọ́ nínú ọ̀rọ̀, ìṣe, ìfẹ́, òtítọ́ àti ìwà mímọ́. \v 13 Títí tí n ó fi dé, tẹ̀ síwájú láti máa ṣe kíkà, àlàyé àti ìkọ́ni Ọlọ́run.

1
04/14.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 14 Má ṣe pa àwọn ẹ̀bùn tí ń bẹ nínú rẹ ti èyí tí a fi fún ọ nípa ìsọtẹ́lẹ̀, pẹ̀lú ìgbọ́wọ́ léni lórí àwọn àgbà. Má se àníyàn àwọn ǹkan wọ̀nyi. Ma gbé nínú wọn, kí ìtẹ̀síwájú rẹ lee farahàn fún gbogbo ènìyàn. \v 15 Fi pẹ̀lẹ́pèlẹ́ kíyèsi arà rẹ àti sí ẹ̀kọ́ rẹ. Tẹ̀síwájú nínú àwọn ǹkan wọ̀nyí. \v 16 Nítorí nípa ṣíṣe bẹ́ẹ̀, ìwọ yóó gba ara rẹ là àti àwọn tí ń tẹ́tí gbọ́ ọ.

1
04/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Orí Kẹrin

1
05/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\c 5 \v 1 Má ṣe bá àgbàlagbà ọkùnrin wí. Dípò, gbàá níyànjú gẹ́gẹ́ bíi bàbá. Gba àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin níyànjú gẹ́gẹ́ bíi arákùnrin. \v 2 Gba àwọn àgbàlagbà obìnrin níyànjú gẹ́gẹ́ bi màmá, àti àwọn ọ̀dọ́mobìnrin gẹ́gẹ́ bíi arábìnrin pẹ̀lú ìwà mímọ́ ní gbogbo ọ̀nà.

1
05/03.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 3 Bu ọlá fún àwọn opó, àwọn opó tòótọ́. \v 4 Ṣùgbọ́n tí opó bá ní àwọn ọmọ tàbí ọmọ-ọmọ, jẹ́ kí wọ́n ó kọ́kọ́ kọ́ bí a tí ń fi ọlá hàn nínú ilé ara wọn. Jẹ́kí wọ́n ó san fún àwọn òbí wọn, nítorí èyí tẹ́ Ọlọ́run lọ́rùn.

1
05/05.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 5 Ṣùgbọ́n opó tòótọ́ wà láì ní ẹnìkankan. Ó fi ìgbẹ́kẹ̀lẹ́ rẹ̀ sínú Ọlọ́run. Óún wá pẹ̀lú ìbéèrè àti àdúrà ní gbogbo ìgbá, lóru àti lọ́sàn. \v 6 Ṣúgbọ̀n, obìnrin tí ń bá ńgbé fún afẹ́ àti ìfẹ́kùfẹ́ ti dòkú bí ótilẹ̀ jọpé ó wà láàyè.

1
05/07.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 7 Wàásù àwọn ǹkan wọ̀nyí kí wọ́n baà le wà láì lẹ́bi. \v 8 Ṣùgbọ́n bí ẹnikẹ́ni kò bá pèsè fún ilé rẹ̀, pàápajàlo àwọn tí ó jẹ́ ará ilé rẹ̀, ó ti sẹ́ ìgbàgbọ́ èyí sì burú jáì ju aláìgbàgbọ́ lọ.

1
05/09.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 9 opóbìnrin fi orúkọ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí opó níwọ̀n ìgbà tí ọjọ́ orí rẹ̀ kò bá tì pé ọgọ́ta, tí ó jẹ́ aya ọlọ́kọ kan. \v 10 A gbọ̀dọ̀ mọ̀ ó fún iṣọ́ rere, yálà òún ṣe ìtọ́jú àwọn ọmọdé tàbí ìgbàlejò àwọn àjòjì, tàbí ó ti farahìn fún iṣẹ́ rere gbogbo.

1
05/11.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 11 fún opó kékeré, ẹ kọ̀ láti fi orúkọ rẹ̀ sílẹ̀. Ńítorí nígbà tí wọn kò si lè máradúró lòdì sí Krístì, wọ́n fẹ́ láti lọ́kọ. \v 12 Ní ọ̀nà yí won yóo gba ìdálẹ́bi nítorí wọ́n ti kọ ìfarajìn àkọ́kọ́ wọn sílẹ̀. \v 13 Wọ́n sì sábà má ń wà lálàì níṣẹ́. Wọ́n á maa lọ kákàkiri sí ilé sí ilé. Kìí sì ṣepé wọn kò níṣẹ́ nìkan, ṣùgbọ́n wọ́n ó di ẹni tí n sọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀ àti alátòjubọ́. Wọ́n ó máa sọ ohun tí kò yẹ kí wọ́n ó sọ.

1
05/14.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 14 Nítorínà mo fẹ́ kí àwọn opó kékèké kí ó lọ́kọ, kí wọ́n ó bímọ, kí wọ́n ó tọ́jú ilé, láti má fi àyè sílẹ̀ fún alátakò láti takò wá nípa ṣíṣe ibi. \v 15 Nítorí àwọn kan ti yà kúrò wọ́n sì tẹ̀lẹ́ sátáni. \v 16 Bí obìnrin onígbàgbọ́ kan bá ní àwọn opó, jẹ́ kó rànwọ́lọ́wọ́, kí ọrún má baà wọ ìjọ, kí ìjọ ba lè ran àwọn opó tòótọ́ lọ́wọ́.

1
05/17.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 17 Ẹbu olá ńlá fún àwọn àgba tí ń ṣe ìdarí dáradára, pàápàá àwọn tí ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ọ̀rọ̀ Ọlọ́run àti nínú ìkọ́ni. \v 18 Nítorí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sọpé "Ẹ̀yin kò gbọdọ̀ so enu màálù tín te oká," àti wípé "Alágbàṣe yẹ fún èrè rẹ̀.

1
05/19.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 19 Má ṣe gba ìfisùn lòdì sí àgbàlagbà bí kòṣe láti enu ẹlẹ́rǐ méjì sí mẹ́ta. \v 20 Bá ẹlẹ́ṣẹ̀ wí ní gbangba kí àwọn ìyókù balè bẹ̀rù.

1
05/21.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 21 Tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ ni mo páá láṣẹ fún o níwájú Ọlọ́run àti níwájú Krístì Jésù àti àwọn ángẹ́lì wọn tí ayàn, wípé kí ó pa àwọn òfin yìí mọ́ láì sí ìkòrira àti kí o sì ṣe ohun gbogbo láì sí ojúṣàájú. \v 22 Má ṣe yára láti gbọ́wọ́ lé ẹnikẹ́ni. Má ṣe pín nínú ẹ̀ṣẹ̀ ẹlòmíràn. Ó ye kí o máa pa ara rẹ́ mọ́.

1
05/23.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 23 Má se mu omi nìkan mọ́. Dípò máa mu wáìnì díẹ̀ fún ikùn rẹ àti fún àwọn àìsàn òrèkóòrè rẹ. \v 24 Ẹ̀ṣẹ̀ àwọn kan jẹ́ èyí tó farahàn, tí wọ́n sì ń ṣíwájú wọn lọ sí ìdájọ́. Ṣùgbọn àwọn ẹ̀ṣẹ̀ kán ń tẹ̀lé wọn tó báyá. \v 25 Bákańnà, àwo.n iṣẹ́ rere kan farahàn, ṣùgbọ́n kódà àwọn èyí tókù náà kò ní farapamọ́.

1
05/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Orín Kaàrún

1
06/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\c 6 \v 1 Jẹ́ kí gbogbo àwọn tó wà nínú àjàgà ẹrú rǏ olúwa wọn gẹ́gẹ́ bi ẹni tó yẹ fún ìyìn. Kí wọ́n ṣe èyí kí orúkọ Ọlọ́run àti ìkónni má ṣe di sí sọ̀rọ̀ òdì sì. \v 2 Àwọn erú tó ní olúwa tí ó gbàgbọ́ kò gbọdọ̀ rí wọ́n fín nítorí wọ́n jẹ́ arákùnrin wọn. Dípò, kí wọ́n tún bọ̀ máa sìn wọ́n síi. Nítorí àwọn olúwa tí a rànlánwọ́ nípa iṣẹ́ wọn jé onígbàgbọ́ àti ẹni ìfẹ́. Kó í o sì sọ àwọn ǹkan wọ̀nyi.

1
06/03.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 3 Bí ẹnikẹ́ni bá n kọ́ ni nì ẹ̀kọ́ ọ̀tọ̀ tí kò si gba ẹ̀kọ́ òtítọ́ wa, èyí nì, ọ̀rọ̀ Ọlúwa wa Jésù Kristì. Bí wọ́n kò bá gba ẹ̀kọ́ tó n yọrísí ìwà-bí-Ọlórun. \v 4 Ẹni na jẹ́ onígbéraga àti aláimọ̀kan. Dípò, ó ní àìsàn pèlú àríyànjiyàn àti ìjìyàn nípa ọ̀rọ̀. Àwọn ọ̀rọ̀ yi já sí ìlara, ìjà, ẹ̀gàn, ìfura ibi àti \v 5 rògbòdìyàn gbogbo ìgbà lárìín àwọn èyàn pèlú ọ̀kàn ibi. Wọ́n lòdì sí òtítọ́. Wọ́n rò wípé ìwà-bí-Ọlórun jé ọ̀na láti di ọlọ́rọ̀.

1
06/06.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 6 Nísisìyí, ìwà-bí-Ọlọ́run pèlú ìtẹ́lọ́rùn jé èrè nlá. \v 7 Nítorí à kò mú ohunkóhun wá sí ayé. Bẹ́ẹ̀ni a kò ní le mú ohunkóhun lọ. \v 8 Dípò, ẹ jé kí á ní ìtẹ́lọ́rùn pèlú óunjẹ àti aṣọ.

1
06/09.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 9 Nísisìyí àwọn tó fẹ́ di ọlọ́rọ̀ ṣubú sínú ìdánwò, sínu pàkúté. Wọ́n ṣubú sínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ òmùgò àti ìfẹ́kúfẹ̌ tí ó ń panilára, àti ohunkóhun tó má ń mú àwọn ènìyàn rì sínú ìparun àti ègbé. \v 10 Nítorí ìfẹ́ owó ni gbòǹgbò ohun búburù gbogbo. Âwọn ènìyàn tí wọ́n nífẹ̌ rẹ̀ ti ṣìnà kúrò nínu ìgbàgbọ́ wọ́n sì ti gún ara wọn pèlú ìbìnújé tó pọ̀.

1
06/11.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 11 Ṣùgbọ́n ìwọ, ènìyàn Ọlórun, sá kúrò fún àwọn ǹkan wọ̀nyí. Lépa òdodo, ìwà bí Ọlórun, ìgbàgbọ́, ìfẹ́, ìfaradà, àti ìwà tútù. \v 12 Jà ìjà tì ìgbàgbọ́. Di ìyè ayérayé èyí tí à pè ó sí mú. Nípa èyí ni o jẹ́ ẹ̀rí níwájú àwọn ẹlẹ́rìí nípa ǹkan tó dára.

1
06/13.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 13 Mo fún yín ní àwọn òfin yì níwájú Ọlọ́run, tí ó sọ ohun gbogbo di ààyè, àti níwájú Kristì Jésù, tí ó sọ òtítọ́ sí Póintù Pílátù: \v 14 pa òfin mọ́ dáradára, láìsí ẹ̀gaǹ, títí di ìfarahán Ọlúwa wa Jésù Kristì.

1
06/15.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 15 Ọlórun yó fi ara Rẹ̀ hàn ni àsìkò tó tọ́--- Ọlórun, Olùbùkún nì, Agbára kan soso, Ọba tó jọba, Olúwa tó darí. \v 16 Òun nìkan ló jẹ́ àìkú tó sin gbé nínú ìmólẹ̀ tí a kò le è sún mọ́. Ènìyàn kankan kò ri tàbí le wòó. Fún òun ni ìyìn àti agbára ayérayé. Àmín

1
06/17.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 17 Ẹ sọ fún àwọn olówo ayé kí wọ́n má ṣe gbéraga, kí wọ́n má ṣe ní ìrètí nínú ọ̀rọ̀, tí kò dájú. Dípò, kí wọ́n ní ìrètí nínú Ọlórun. Ó pèsè ọrọ̀ òtítọ́ fún wa láti le gbádùn. \v 18 Sọ fún wọn kí wọ́n má a se oore, kí wọ́n jẹ́ ọlọ́rọ̀ nínú iṣẹ́ dáradàra, láti jẹ́ onínúrere, àti láti ṣe tán láti pín. \v 19 Ní ọ̀nà náà, wọ́n yó to ìpìnlẹ̀ dáradára fún ara wọn fún èyí tí ó ń bọ̀, ki wọ́n lè di ìyè òtítọ́ mu.

1
06/20.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 20 Tímótìù, pa ǹkan tí a fí fun ọ mọ́. Yàgò fún ọ̀rọ̀ òmùgọ̀ àti àríyànjiyàn tí o lòdì nípa nǹkan tí à ń fi èké pè ní ìmọ̀. \v 21 Àwọn ènìyàn kan kéde àwọn ǹkan wọ̀nyi wọ́n sì ti sìnà ìgbàgbọ́. Kí oreọ̀fẹ́ ó wà pèlù yín.

1
06/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Orí Kẹfà

View File

@ -34,7 +34,11 @@
"parent_draft": {},
"translators": [
"Adio F. Oluwatobiloba ",
"adiofunmiladeo"
"adiofunmiladeo",
"Adesina Abegunde",
"Tobyno88",
"adesinaabegunde",
"adesina abegunde"
],
"finished_chunks": [
"front-title",
@ -51,6 +55,43 @@
"02-05",
"02-08",
"02-11",
"02-13"
"02-13",
"03-title",
"03-01",
"03-04",
"03-06",
"03-08",
"03-11",
"03-14",
"03-16",
"04-title",
"04-01",
"04-03",
"04-06",
"04-09",
"04-11",
"04-14",
"05-title",
"05-01",
"05-03",
"05-05",
"05-07",
"05-09",
"05-11",
"05-14",
"05-17",
"05-19",
"05-21",
"05-23",
"06-title",
"06-01",
"06-03",
"06-06",
"06-09",
"06-11",
"06-13",
"06-15",
"06-17",
"06-20"
]
}