adesinaabegunde_yo_1ti_text.../04/14.txt

1 line
542 B
Plaintext

\v 14 Má ṣe pa àwọn ẹ̀bùn tí ń bẹ nínú rẹ ti èyí tí a fi fún ọ nípa ìsọtẹ́lẹ̀, pẹ̀lú ìgbọ́wọ́ léni lórí àwọn àgbà. Má se àníyàn àwọn ǹkan wọ̀nyi. Ma gbé nínú wọn, kí ìtẹ̀síwájú rẹ lee farahàn fún gbogbo ènìyàn. \v 15 Fi pẹ̀lẹ́pèlẹ́ kíyèsi arà rẹ àti sí ẹ̀kọ́ rẹ. Tẹ̀síwájú nínú àwọn ǹkan wọ̀nyí. \v 16 Nítorí nípa ṣíṣe bẹ́ẹ̀, ìwọ yóó gba ara rẹ là àti àwọn tí ń tẹ́tí gbọ́ ọ.