yo_eph_text_reg/06/19.txt

1 line
427 B
Plaintext

\v 19 Kí ẹ sì gbàdúrà fún mi, pé kí á leè fún mi ní isẹ́ ìránsẹ́ kan nígbàtí mo bá ya ẹnu mi. Ẹ gbàdúrà pé kí n leè ma sọọ́ di mímọ̀ pẹ̀lú ìgboyà àwọn òtítọ́ náà tí ó pamọ́ nípa ìyìnrere. \v 20 Nítorí ìyìnrere ni mo se di ikọ̀ tí a pamọ́ nínú ìdè, kí n leè máa sọọ́ pẹ̀lú ìgboyà, gẹ́gẹ́bí ó se yẹ kí n sọ̀rọ̀.