yo_eph_text_reg/06/12.txt

1 line
438 B
Plaintext

\v 12 Nítorí kìí se ẹran ara àti ẹ̀jẹ̀ ni àwa ḿbá jìjàdadì, bíkòse àwọn ìjọba, àwọn alásẹ, àti àwọn alákòso ẹ̀mí nínú òkùnkùn, àti àwọn ẹ̀mí búburú nínú àwọn ọ̀run. \v 13 Nítorínáà, ẹ gbé gbogbo ìhàmọ́ra Ọlọ́run wọ̀, kí ẹ̀yin kí ó leè dúró nínú àkókò ibi yìí, àti lẹ́yìn tí ẹ bá ti se ohun gbogbo tán, láti dúró gírí.