yo_eph_text_reg/05/22.txt

1 line
443 B
Plaintext

\v 22 Ẹ̀yin aya ẹ jọ̀wọ́ ara yín fún àwọn ọkọ yín, gẹ́gẹ́bí fún Olúwa. \v 23 Nítorí ọkọ ní íse orí aya gẹ́gẹ́bí Krístì pẹ̀lú se jẹ́ orí fún ìjọ àti Krístì fúnrarẹ̀ ni Olùgbàlà ìjọ. \v 24 Gẹ́gẹ́bí ìjọ se jọ̀wọ́ ara rẹ̀ fún Krístì bẹ́ẹ̀ pẹ̀lu àwọn aya gbọ́dọ̀ jọ̀wọ́ ara wọn fún àwọn ọkọ wọn nínú ohun gbogbo.