yo_eph_text_reg/04/09.txt

1 line
267 B
Plaintext

\v 9 Kí ni ìtumọ̀ wípé: "Ó gòkè," bíkòsepé ó sọ̀kalẹ̀ pẹ̀lú lọ sí ibi tí ó rẹlẹ̀ jùlọ nínú ayé? \v 10 Ẹnití ó sọ̀kalẹ̀, ohun kanna ni ẹnití ó gòkè rékọjá àwọn ọ̀run, kí ó baà le kún ohun gbogbo .