yo_eph_text_reg/04/01.txt

1 line
416 B
Plaintext

\c 4 \v 1 Èmi, nítorínáà, gẹ́gẹ́bí ẹlẹ́wọ̀n fún Olúwa, ńrọ̀ yín láti rìn ní yíyẹ fún ìpè yín tí a fi pè yín. \v 2 Mo rọ̀ yín kí ẹ gbé ìgbé ayé ìrẹ̀lẹ̀ tí ó tóbi pẹ̀lú ìfarabalẹ̀ àti sùùrù, kí á máa gbé pẹ̀lú omonìkẹ̀jì wa pẹ̀lú ìfẹ́. \v 3 Se aápọn láti pa ìsọ̀kan ti Ẹ̀mí mọ́ níní ìdè ṣ`àláfìa.