yo_eph_text_reg/03/20.txt

1 line
291 B
Plaintext

\v 20 Ǹjẹ́ nísinsìnyí, sí ẹnití ó lè se gidigidi ju ohun gbogbo tí a nbéèrè, tàbí tí a ń rò, gẹ́gẹ́bí agbára tí ó ńsisẹ́ nínú wa \v 21 Ohun ni ògo wà fún nínú ìjọ àti nínú Krístì Jésù sí gbogbo ìrandíra laí àti laílaí, àmín.