yo_eph_text_reg/03/10.txt

1 line
283 B
Plaintext

\v 10 Ète yìí ni a sọ di mímọ̀ nipaseẹ̀ ìjọ, kí àwọn ìjoba àti alásẹ ní àwọn ọ̀run leè mọ̀ irúfẹ́ ìsẹ̀dá ọgbọ́n Ọlọ́run. \v 11 Èyí sẹlẹ̀ gẹ́gẹ́bí ète ayérayé tí ó di mímúse nínú Krístì Jésù Olúwa wa.