yo_eph_text_reg/03/03.txt

1 line
516 B
Plaintext

\v 3 Mo ń kọ̀wé gẹ́gẹ́bí ìfihàn tí a mú kí n mọ̀. Èyí ni òtítọ́ tí ó pamọ́, tí mo kọ̀wé rẹ̀ sí yín ní kía. \v 4 Nígbàtí ẹ bá ka èyí, yóò le yé yín, òye ti mo ní nípa òtítọ́ tí o pamọ́ nípa Krístì. \v 5 Ní àwon ìran míran, òtítọ́ yìí kò di mímọ̀ sí àwọn ọmọ ènìyaàn. Sùgbọ́n nísinsìnyí, ó ti di fífihàn nípa Ẹ̀mí sí àwọn àpòstélì àti wòólì tí a yà sọ́tọ̀ fún isẹ́ yìí.