yo_eph_text_reg/03/01.txt

1 line
235 B
Plaintext

\c 3 \v 1 Nítorí ìdí èyí, èmi Pọ́ọ̀lù, ẹlẹ́wọ̀n Jesù Krístì ni mí fún àwọn Kèfèrí \v 2 Mo lérò wípé ẹ ti gbọ́ nípa ìrìjú ti ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run tí a fi fún mi nítorí tiyín.