yo_eph_text_reg/02/17.txt

1 line
242 B
Plaintext

\v 17 Jésù wá, ó polongo àlàfia fún ẹ̀yin tí ó wà ní ọ̀nà jíjìn réré àti àláfià fún àwọn tí ó wà ní ìtòsí. \v 18 Nítorí nípasẹ̀ Jésù, gbogbo wa ni ọ̀nà sí ipa ẹ̀mí kan sí ọdọ Baba.