yo_eph_text_reg/02/08.txt

1 line
451 B
Plaintext

\v 8 Nítorí nípa ore ọ̀fẹ́ ni a ti fi gbà yín là, nípa ìgbàgbọ́, èyí kò sì ti ọ̀dọ̀ yín wá, ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run ni. \v 9 Ore ọfẹ́ kò ti ipa isẹ́ wá nítorináà ẹnìkan kò leè sògo. \v 10 Nítorí isẹ́ ọwọ́ Rẹ̀ ni wá, tí a dá nínú Krístì Jésù láti se isẹ́ rere tí Ọlọ́run se èètò fún láti ọjọ́ tó ti pẹ́ fún wa, kí àwa kí ó lè rìn nínú won.