yo_eph_text_reg/01/22.txt

1 line
216 B
Plaintext

\v 22 Ọlọ́run fi ohun gbogbo sí abẹ́ ẹsẹ̀ Krístì, Ó sì fi I fún ìjọ gẹ́gẹ́bí Orí ohun gbogbo. \v 23 Ìjọ jẹ́ ara Rẹ̀, kíkún ẹnití ó kún ohun gbogbo nínú ohun gbogbo.