yo_eph_text_reg/01/17.txt

1 line
412 B
Plaintext

\v 17 Mo ń gbàdúrà pé kí Ọlọ́run Olúwa wa Jésù Krístì, Baba ògo, kí ó fún yín ní ẹ̀mí Ọgbọ́n àti ìfihàn ninú ìmọ̀ òun tìkálára Rẹ̀. \v 18 Mo gbàdúrà kí ojú inú ọkàn yín kí ó lè gba ìtúnríran, ki eyin kí ó lè mọ ìdánilójú ìrètí tí ó ti fi pè yín sí àti ọrọ̀ náà, ti ogún tí ó ni ògo láàrin àwon ènìyàn mímọ́.