yo_eph_text_reg/01/09.txt

1 line
343 B
Plaintext

\v 9 Ọlọ́run sọ di mímọ́ fún wa, ète ìfẹ́ Rẹ̀ ti o wà nínú ìpamọ́ gẹ́gẹ́bí ohun tí o wù ún, ti o si ti se àfihàn rẹ̀ nínú Krístì, \v 10 Pẹ̀lú èròngbà láti pinnu fún kíkún àkókò, láti mú ohun gbogbo papọ̀, tí ḿbẹ ní ọ̀run àti ní ayé lábẹ́ Krístì ti i se Orí.