yo_eph_text_reg/01/03.txt

1 line
314 B
Plaintext

\v 3 Kí Ọlọ́run àti Baba Jésù Krístì Olúwa gba ògo, ẹnití ó ti bùkún wà pẹ̀lú gbogbo ìbùkún ti ẹ̀mí nínú àwọn ọ̀run nínú Krístì. \v 4 Ọlọ́run yàn wa nínú rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ ayé, pé kí àwa lè jẹ́ mímọ́ àti aláìlàbúkù níwájú rẹ̀.