yo_eph_text_reg/01/01.txt

1 line
318 B
Plaintext

\c 1 \v 1 Pọ́ọ̀lù, ìránsẹ́ Krístì Jésù nípa ìfẹ́ Ọlọ́run, sí àwọn ènìyàn, Ọlọ́run, mímọ́ tí ó wà ní Éfésù, tí won se olóòtọ́ nínú Krístì Jésù. \v 2 Ore ọ̀fẹ́ sí yín àti àláfià láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba wa àti Olúwa Jésù Krístì.