yo_eph_text_reg/06/23.txt

1 line
283 B
Plaintext

\v 23 Àláìia fún gbogbo àwon arákùnrin, àti ìfẹ́ pẹ̀lú ìgbàgbọ́ láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba àti Olúwa Jésù Krístì. \v 24 Ki ore ọ̀fẹ́ kí ó wà pẹ̀lú gbogbo àwọn tí ó fẹ́ Olúwa Jésù Krístì pẹ̀lú ìfẹ́ tí kìí kú.