yo_eph_text_reg/06/14.txt

1 line
402 B
Plaintext

\v 14 Ẹ dúró, nítorínáà, lẹ́yìn ìgbà tí ẹ bá ti fi ọ̀já ìgbànú ti òtítọ́ àti ìgbayà tí òdodo nì mọ́ ara. \v 15 Bẹ́ẹ̀ni bàtà fún ẹsẹ̀ yín, ẹ gbé ìmúra tó setán láti polungo ìyìnrere ti àláìia wọ̀. \v 16 Ní gbogbo ohunkóhun ẹ mú apata ìgbàgbọ́, nípa èyí tí ẹ̀yin yóò fi leè pa iná àwọn ọfà ẹni ibi nì.