yo_eph_text_reg/06/09.txt

1 line
225 B
Plaintext

\v 9 Ẹ̀yin ọ̀gá, ẹ tọ́jú àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ bákannáà. Ẹ máse halẹ̀ mọ́ won. Ẹ kúkú mọ̀ wípé ọ̀gá ẹ̀yin méjèjì wà ní ọ̀run, kò sì sí ojúsàájú pẹ̀lú Rẹ̀