yo_eph_text_reg/01/13.txt

1 line
349 B
Plaintext

\v 13 Nínú Krístì, ẹ̀yin pẹ̀lu, nígbàtí ẹ ti gbọ́ ọ̀rọ̀ òtìtọ́, ìhìnrere ìgbàlà náà, ẹ ní ìgbàgbọ́ nínú Rẹ̀, a sì fi Ẹmi Mimo ti a sèlèrí se èdìdí yín. \v 14 Ẹnití o se ìdánilojú ogún tí a jẹ títí ìgbà tí a ó fi ogún náà sí abẹ́ ìsàkoso wa sí ìyìn ògo Rẹ̀.