yo_eph_text_reg/01/11.txt

1 line
314 B
Plaintext

\v 11 Nínú Krístì a yàn wá láti jẹ́ ajogún. Ati se ìpinnu síwájú àkókò gẹ́gẹ́bí ète Rẹ̀, ẹnití o se ìgbéjáde ohun gbogbo gẹ́gẹ́bí ìpinnu ìfẹ́ Rẹ̀. \v 12 Ọlọrun yàn wa gẹgẹbí ajogún ìrètí nínú Krístì, kí àwa ba leè jẹ́ ìyìn ògo Rẹ̀.