yo_eph_text_reg/01/05.txt

1 line
302 B
Plaintext

\v 5 Ọlọ́run yàn wá síwájú àkókò fún ìsọdọmọ láti jẹ́ ọmọ nípasẹ̀ Jésù Krístì, gẹ́gẹ́bí ìfẹ́ inú rere ti ifẹ́ Rẹ̀ \v 6 Ìsọdọmọ wa yọrí sí ìyìn ògo ore - ọ̀fẹ́ Rẹ̀ tí ó fi fún wa lọfẹ nínú Ẹnití ó fẹ́ràn.