commit e736524faf1cf84e3cba2d9284bf5e928bbe0d2f Author: scunningham Date: Mon Jun 21 12:29:28 2021 -0400 Mon Jun 21 2021 12:29:28 GMT-0400 (EDT) diff --git a/01/01.txt b/01/01.txt new file mode 100644 index 0000000..066a33c --- /dev/null +++ b/01/01.txt @@ -0,0 +1 @@ +\c 1 \v 1 Pọ́ọ̀lù, ìránsẹ́ Krístì Jésù nípa ìfẹ́ Ọlọ́run, sí àwọn ènìyàn, Ọlọ́run, mímọ́ tí ó wà ní Éfésù, tí won se olóòtọ́ nínú Krístì Jésù. \v 2 Ore ọ̀fẹ́ sí yín àti àláfià láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba wa àti Olúwa Jésù Krístì. \ No newline at end of file diff --git a/01/03.txt b/01/03.txt new file mode 100644 index 0000000..374cbde --- /dev/null +++ b/01/03.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 3 Kí Ọlọ́run àti Baba Jésù Krístì Olúwa gba ògo, ẹnití ó ti bùkún wà pẹ̀lú gbogbo ìbùkún ti ẹ̀mí nínú àwọn ọ̀run nínú Krístì. \v 4 Ọlọ́run yàn wa nínú rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ ayé, pé kí àwa lè jẹ́ mímọ́ àti aláìlàbúkù níwájú rẹ̀. \ No newline at end of file diff --git a/01/05.txt b/01/05.txt new file mode 100644 index 0000000..9785598 --- /dev/null +++ b/01/05.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 5 Ọlọ́run yàn wá síwájú àkókò fún ìsọdọmọ láti jẹ́ ọmọ nípasẹ̀ Jésù Krístì, gẹ́gẹ́bí ìfẹ́ inú rere ti ifẹ́ Rẹ̀ \v 6 Ìsọdọmọ wa yọrí sí ìyìn ògo ore - ọ̀fẹ́ Rẹ̀ tí ó fi fún wa lọfẹ nínú Ẹnití ó fẹ́ràn. \ No newline at end of file diff --git a/01/07.txt b/01/07.txt new file mode 100644 index 0000000..8939eff --- /dev/null +++ b/01/07.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 7 Nínú Jésù Krístì àwá ni ìràpadà nípa ẹ̀jẹ̀ àti nípa ìdáríjìn ẹ̀sẹ̀ wa gbogbo nípa ọ̀rọ̀ ore ọ̀fẹ́ Rẹ̀. \v 8 Ó tú ore ọ̀fẹ́ Rẹ̀ lé wa lórí pẹ̀lú gbogbo ọgbọ́n àti òye. \ No newline at end of file diff --git a/01/09.txt b/01/09.txt new file mode 100644 index 0000000..b794112 --- /dev/null +++ b/01/09.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 9 Ọlọ́run sọ di mímọ́ fún wa, ète ìfẹ́ Rẹ̀ ti o wà nínú ìpamọ́ gẹ́gẹ́bí ohun tí o wù ún, ti o si ti se àfihàn rẹ̀ nínú Krístì, \v 10 Pẹ̀lú èròngbà láti pinnu fún kíkún àkókò, láti mú ohun gbogbo papọ̀, tí ḿbẹ ní ọ̀run àti ní ayé lábẹ́ Krístì ti i se Orí. \ No newline at end of file diff --git a/01/11.txt b/01/11.txt new file mode 100644 index 0000000..62f8b65 --- /dev/null +++ b/01/11.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 11 Nínú Krístì a yàn wá láti jẹ́ ajogún. Ati se ìpinnu síwájú àkókò gẹ́gẹ́bí ète Rẹ̀, ẹnití o se ìgbéjáde ohun gbogbo gẹ́gẹ́bí ìpinnu ìfẹ́ Rẹ̀. \v 12 Ọlọrun yàn wa gẹgẹbí ajogún ìrètí nínú Krístì, kí àwa ba leè jẹ́ ìyìn ògo Rẹ̀. \ No newline at end of file diff --git a/01/13.txt b/01/13.txt new file mode 100644 index 0000000..0672d6c --- /dev/null +++ b/01/13.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 13 Nínú Krístì, ẹ̀yin pẹ̀lu, nígbàtí ẹ ti gbọ́ ọ̀rọ̀ òtìtọ́, ìhìnrere ìgbàlà náà, ẹ ní ìgbàgbọ́ nínú Rẹ̀, a sì fi Ẹmi Mimo ti a sèlèrí se èdìdí yín. \v 14 Ẹnití o se ìdánilojú ogún tí a jẹ títí ìgbà tí a ó fi ogún náà sí abẹ́ ìsàkoso wa sí ìyìn ògo Rẹ̀. \ No newline at end of file diff --git a/01/15.txt b/01/15.txt new file mode 100644 index 0000000..99292a9 --- /dev/null +++ b/01/15.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 15 Fún ìdí èyí, láti ìgbà tí mo ti gbọ́ nípa ìgbàgbọ́ yín nínú Olúwa Jésù àti ìfẹ́ yín fún gbogbo àwon ènìyàn mímọ́. \v 16 N kò tíì dẹ́kun láti dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run bí mo se n dárúko yín nínú àwon àdúrà mi. \ No newline at end of file diff --git a/01/17.txt b/01/17.txt new file mode 100644 index 0000000..3a24dc0 --- /dev/null +++ b/01/17.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 17 Mo ń gbàdúrà pé kí Ọlọ́run Olúwa wa Jésù Krístì, Baba ògo, kí ó fún yín ní ẹ̀mí Ọgbọ́n àti ìfihàn ninú ìmọ̀ òun tìkálára Rẹ̀. \v 18 Mo gbàdúrà kí ojú inú ọkàn yín kí ó lè gba ìtúnríran, ki eyin kí ó lè mọ ìdánilójú ìrètí tí ó ti fi pè yín sí àti ọrọ̀ náà, ti ogún tí ó ni ògo láàrin àwon ènìyàn mímọ́. \ No newline at end of file diff --git a/01/19.txt b/01/19.txt new file mode 100644 index 0000000..a561fd3 --- /dev/null +++ b/01/19.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 19 Nínú àdúrà mi, mo béèrè wípé kí ẹ̀yin kí ó lè mọ títóbi agbára Rẹ̀ tí kó ní òsùnwọ̀n nínú àwa tí ó gbàgbọ́ gẹ́gẹ́bí síse isẹ́ títóbi nípa okun Rẹ̀. \v 20 Èyí ni òduwọ̀n agbára kannà tí Ọlọ́run fi sisẹ́ nínú Krístì, nígbàtí Ó jíi dìde nínú àwọn òkú tí ó sì mú kí ó jòkó ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹ̀ nínú àwon ọ̀run. \v 21 Ó mú kí Krístì jòkó rékọjá gbogbo ìsàkoso àti àsẹ àti agbára, àti ìjọba àti orúkọ kórukọ́ tí a lè dá. Krístì yóò se àkoso, kìí se ní ayé yìí nìkan ṣùgbọ́n, kódà ní ayé tí ḿbọ̀ pẹ̀lú. \ No newline at end of file diff --git a/01/22.txt b/01/22.txt new file mode 100644 index 0000000..6b1cf43 --- /dev/null +++ b/01/22.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 22 Ọlọ́run fi ohun gbogbo sí abẹ́ ẹsẹ̀ Krístì, Ó sì fi I fún ìjọ gẹ́gẹ́bí Orí ohun gbogbo. \v 23 Ìjọ jẹ́ ara Rẹ̀, kíkún ẹnití ó kún ohun gbogbo nínú ohun gbogbo. \ No newline at end of file diff --git a/01/title.txt b/01/title.txt new file mode 100644 index 0000000..cff0527 --- /dev/null +++ b/01/title.txt @@ -0,0 +1 @@ +Orí Kìnńí \ No newline at end of file diff --git a/02/01.txt b/02/01.txt new file mode 100644 index 0000000..7de8295 --- /dev/null +++ b/02/01.txt @@ -0,0 +1 @@ +\c 2 \v 1 Sùgbọ́n nípa ti yín, ẹ̀yin ti kú nínú ẹsẹ àti ìrékojá yín. \v 2 Nínú ẹ̀sẹ̀ àti ìrékojá wọ̀nyí ni ẹ ń gbé gẹ́gẹ́bí ìse ti ayé yǐ. Ẹ̀yin ńgbé ayé gẹ́gẹ́bí fún alákoso àti àwon alásẹ òfúrufú, èmi náà tí ńsisẹ́ nínú àwọn ọmọ aláìgbọràn. \v 3 Nígbà kan rí, gbogbo wa n gbé láàrin àwọn ènìyàn wọ̀nyí, nípa mímú ìfẹ́ burúkú ti ẹ̀dá ẹ̀sẹ̀ wá sí síse, àti láti máa mú ìfẹ́ ti ara àti ti ọkàn wá sí ìmúsẹ. Nípa ìsẹ̀dá ọmọ ìbínú, gẹ́gẹ́bí gbogbo ẹ̀dá ènìyàn. \ No newline at end of file diff --git a/02/04.txt b/02/04.txt new file mode 100644 index 0000000..4bc300d --- /dev/null +++ b/02/04.txt @@ -0,0 +1,2 @@ +\v 4 Sùgbọ́n Ọlọ́run nínú ọrọ̀ àánú Rẹ̀, àti nítorí ìfẹ́ Rẹ̀ títóbi, tí ó fi fẹ́ wa. \v 5 Nígbàtí a ti kú nínú ìrékojá ó mú wa wà láàyè papọ̀ nínú Krístì, nípa ore ọ̀fẹ́ a gbà yín là. \v 6 Ọlọ́run jí wa dìde papọ̀ pẹ̀lú Krístì, Ọlọ́run sí mú wa jókò papọ̀ nínú àwọn ọ̀run nínú Krístì Jesu. +su. \v 7 Ki o ba le jẹ́ wípeeé ni ayé ti ḿbọ̀, kí òhun kí ó leè fihàn wa , ọrọ̀ àánú Rẹ̀ tí ó tóbi láìlósùnwọ̀n ore ọ̀fẹ́ tí ó ti sọ nípa inú rere Rẹ̀ sí wa nínú Krístì Jésù. \ No newline at end of file diff --git a/02/08.txt b/02/08.txt new file mode 100644 index 0000000..505a768 --- /dev/null +++ b/02/08.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 8 Nítorí nípa ore ọ̀fẹ́ ni a ti fi gbà yín là, nípa ìgbàgbọ́, èyí kò sì ti ọ̀dọ̀ yín wá, ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run ni. \v 9 Ore ọfẹ́ kò ti ipa isẹ́ wá nítorináà ẹnìkan kò leè sògo. \v 10 Nítorí isẹ́ ọwọ́ Rẹ̀ ni wá, tí a dá nínú Krístì Jésù láti se isẹ́ rere tí Ọlọ́run se èètò fún láti ọjọ́ tó ti pẹ́ fún wa, kí àwa kí ó lè rìn nínú won. \ No newline at end of file diff --git a/02/11.txt b/02/11.txt new file mode 100644 index 0000000..95ba9c9 --- /dev/null +++ b/02/11.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 11 Nítorínaáà ẹ rántí wípé nígbàkan rí, ẹ jẹ́ kèfèrí nínú ara. A pè yín ní "aláìkọ̀là" nípa ohun tí a pè ní "ìkọ̀là" nínú ara tí a se nípa ọwọ́ ènìyàn. \v 12 Ní ìgbànáà ẹ wà ní ìyapa pẹ̀lú Krístì. Ẹ jẹ́ àlejò sí àwọn ara Isrẹlì. Ẹ jẹ́ àlejò sí majẹ̀mu náà tí a ti se ìlérí. Ẹ kò ní ìrètí kan fún ọjọ́ ọ̀la, Ẹ sì wà láìní Ọlọ́run nínú ayé. \ No newline at end of file diff --git a/02/13.txt b/02/13.txt new file mode 100644 index 0000000..1cc1b0d --- /dev/null +++ b/02/13.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 13 Sùgbọ́n nísinsìnyí nínú Krístì Jésù ẹ̀yin tí ó ti jìnnà réré nígbàkanrí sí Ọlọ́run, ẹ̀jẹ̀ Jésù ti mú yín wá sí ìtòsí. \v 14 Nítorí ohun ni àláfìa wa. Ó ti sọ àwon mejèjì di ẹyọkan, nípa ara Rẹ̀, ó ti wó ògiri ìkórira, ìsọ̀tá tí ó pín wa níyà. \v 15 Èyí ní wípé, ó pa òfin, àsẹ àtọwọ́dọ́wọ́ run kí ó ba lé ọ̀tá okùnrin titun kan nínú ara Rẹ̀, kí ó ba le se aláfìa. \v 16 Krístì se ìlàjà àwọn ènìyàn sínú ara kan sí Ọlọ́run nípasẹ̀ àgbèlébù, ó ti pa ìkórira. \ No newline at end of file diff --git a/02/17.txt b/02/17.txt new file mode 100644 index 0000000..2be79d9 --- /dev/null +++ b/02/17.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 17 Jésù wá, ó polongo àlàfia fún ẹ̀yin tí ó wà ní ọ̀nà jíjìn réré àti àláfià fún àwọn tí ó wà ní ìtòsí. \v 18 Nítorí nípasẹ̀ Jésù, gbogbo wa ni ọ̀nà sí ipa ẹ̀mí kan sí ọdọ Baba. \ No newline at end of file diff --git a/02/19.txt b/02/19.txt new file mode 100644 index 0000000..ff12aa3 --- /dev/null +++ b/02/19.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 19 Nítorínáà nísinsìnyí, ẹ̀yin Kèfèrí kìí se àlejò àti àjèjì mọ dipo bẹ́ẹ̀ ẹ ti di ọmọ ìbílẹ̀ kanna pẹ̀lú àwọn ènìyàn mímọ àti ọmọ agbo ile Ọlọ́run. \v 20 A ti kó yin lé orí ìpìlẹ̀ àwọn Aposteli àti àwọn wóòli, ati Kristi Jesu funrarẹ si ni okuta igun ilé. \v 21 Nínú Rẹ gbogbo ilé ẹ di ara won papo, o si n dagba gẹ́gẹ́bí Tẹ́mpìlì nínú Oluwa. \v 22 Nínú Rẹ̀ ni a ti ń kọ́ ẹ̀yín pẹ̀lú papo gẹ́gẹ́bí ibùgbé fún Ọlọ́run nínú Ẹ̀mí. \ No newline at end of file diff --git a/02/title.txt b/02/title.txt new file mode 100644 index 0000000..14f1d5c --- /dev/null +++ b/02/title.txt @@ -0,0 +1 @@ +Orí Kejì \ No newline at end of file diff --git a/03/01.txt b/03/01.txt new file mode 100644 index 0000000..ac1fbf9 --- /dev/null +++ b/03/01.txt @@ -0,0 +1 @@ +\c 3 \v 1 Nítorí ìdí èyí, èmi Pọ́ọ̀lù, ẹlẹ́wọ̀n Jesù Krístì ni mí fún àwọn Kèfèrí \v 2 Mo lérò wípé ẹ ti gbọ́ nípa ìrìjú ti ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run tí a fi fún mi nítorí tiyín. \ No newline at end of file diff --git a/03/03.txt b/03/03.txt new file mode 100644 index 0000000..5535b57 --- /dev/null +++ b/03/03.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 3 Mo ń kọ̀wé gẹ́gẹ́bí ìfihàn tí a mú kí n mọ̀. Èyí ni òtítọ́ tí ó pamọ́, tí mo kọ̀wé rẹ̀ sí yín ní kía. \v 4 Nígbàtí ẹ bá ka èyí, yóò le yé yín, òye ti mo ní nípa òtítọ́ tí o pamọ́ nípa Krístì. \v 5 Ní àwon ìran míran, òtítọ́ yìí kò di mímọ̀ sí àwọn ọmọ ènìyaàn. Sùgbọ́n nísinsìnyí, ó ti di fífihàn nípa Ẹ̀mí sí àwọn àpòstélì àti wòólì tí a yà sọ́tọ̀ fún isẹ́ yìí. \ No newline at end of file diff --git a/03/06.txt b/03/06.txt new file mode 100644 index 0000000..36694a0 --- /dev/null +++ b/03/06.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 6 Òtítọ́ tí ó pamọ́ yìí ni wípé, àwọn kèfèrí pẹ̀lú àwọn ajogún àti àwọn akẹgbẹ́, àti pé wọ́n pín nínú ìlèrí tí ó wà nínú Krístì Jésù nípa ti ìhìnrere náà. \v 7 Nítorí mo di ìránsẹ́ ìhìnrere nípa ẹ̀bùn ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run tí a fi fún mi nípa isẹ́ agbára Rẹ̀. \ No newline at end of file diff --git a/03/08.txt b/03/08.txt new file mode 100644 index 0000000..352b2e1 --- /dev/null +++ b/03/08.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 8 Ọlọ́run fún mí ní ẹ̀bùn yìí bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé èmi ni ó kéré jù nínú àwon ènìyàn, Ọlọ́run, mímọ́. Ẹ̀bùn yìí ni wípé, mo gbọ́dọ̀ kéde ìjìnlẹ̀ ọ̀rọ̀ ìhìnrere Krístì sí àwon Kèfèrí. \v 9 Ẹ̀bùn Ọlọ́run fún mi ní wípé n gó mú ẹnìkọ̀kan wá sínú ìmọ́lẹ̀ ohun tí ète Ọlọ́run jẹ́. Ète yìí tí wà nínú ìpamọ́ láti aìmoye ọdún sẹ́yìn nípa Ọlọ́run tí ó dá ohun gbogbo. \ No newline at end of file diff --git a/03/10.txt b/03/10.txt new file mode 100644 index 0000000..e288bd8 --- /dev/null +++ b/03/10.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 10 Ète yìí ni a sọ di mímọ̀ nipaseẹ̀ ìjọ, kí àwọn ìjoba àti alásẹ ní àwọn ọ̀run leè mọ̀ irúfẹ́ ìsẹ̀dá ọgbọ́n Ọlọ́run. \v 11 Èyí sẹlẹ̀ gẹ́gẹ́bí ète ayérayé tí ó di mímúse nínú Krístì Jésù Olúwa wa. \ No newline at end of file diff --git a/03/12.txt b/03/12.txt new file mode 100644 index 0000000..57fc59f --- /dev/null +++ b/03/12.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 12 Nítorí nínú Krístì a ní ìgboyà àti ọ̀nà pẹ̀lú ìkiniláyà nítorí ìgbàgbọ́ wa nínú Rẹ̀, \v 13 Nítorínáà, mo béèrè wípé kí ẹ máse rẹ̀wẹ̀sì nítorí, ohun tí mo ńjìyà fún yín, èyí tí íse ògo yín. \ No newline at end of file diff --git a/03/14.txt b/03/14.txt new file mode 100644 index 0000000..87e1614 --- /dev/null +++ b/03/14.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 14 Nítorí ìdí èyí, mo wà lórí orúnkún mi sí Baba. \v 15 Láti ọ̀dọ̀ ẹnití a ti sọ gbogbo ìdílé ní Ọ̀run àti ní aye ní orúkọ. \v 16 Mo gbàdúrà pé kí O fifún yín gẹ́gẹ́bí ọrọ̀ ògo Rẹ̀, kí ó fún yín ní okun pẹ̀lú agbára nípa Ẹ̀mí Rẹ̀ tí ó wà nínú yín. \ No newline at end of file diff --git a/03/17.txt b/03/17.txt new file mode 100644 index 0000000..f0f5312 --- /dev/null +++ b/03/17.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 17 Mo gbàdúrà kí Krístì lè gbé nínú ọkàn yín nípa ìgbàgbọ́, pé kí ẹ lè ta gbòngbò mọ́lẹ̀, kí á sì gún yín kúnná nínú ìfẹ́. \v 18 Kí ó fún yín ní ọkun, kí òye kí ó leè yé yín pẹ̀lú gbogbo àwọn onígbàgbọ́, kí ni fífẹ̀, gígùn, gíga, àti jíjìn \v 19 Àti pé kí ẹ̀yin kí ó lè mọ̀ ìfẹ́ Krístì tí ó tayọ ìmọ̀, àti wípé kí á lè fún yín pẹ̀lú gbogbo ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Ọlọ́run. \ No newline at end of file diff --git a/03/20.txt b/03/20.txt new file mode 100644 index 0000000..f715e72 --- /dev/null +++ b/03/20.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 20 Ǹjẹ́ nísinsìnyí, sí ẹnití ó lè se gidigidi ju ohun gbogbo tí a nbéèrè, tàbí tí a ń rò, gẹ́gẹ́bí agbára tí ó ńsisẹ́ nínú wa \v 21 Ohun ni ògo wà fún nínú ìjọ àti nínú Krístì Jésù sí gbogbo ìrandíra laí àti laílaí, àmín. \ No newline at end of file diff --git a/03/title.txt b/03/title.txt new file mode 100644 index 0000000..633cead --- /dev/null +++ b/03/title.txt @@ -0,0 +1 @@ +Orí Ìkẹ́ta \ No newline at end of file diff --git a/04/01.txt b/04/01.txt new file mode 100644 index 0000000..6f8d707 --- /dev/null +++ b/04/01.txt @@ -0,0 +1 @@ +\c 4 \v 1 Èmi, nítorínáà, gẹ́gẹ́bí ẹlẹ́wọ̀n fún Olúwa, ńrọ̀ yín láti rìn ní yíyẹ fún ìpè yín tí a fi pè yín. \v 2 Mo rọ̀ yín kí ẹ gbé ìgbé ayé ìrẹ̀lẹ̀ tí ó tóbi pẹ̀lú ìfarabalẹ̀ àti sùùrù, kí á máa gbé pẹ̀lú omonìkẹ̀jì wa pẹ̀lú ìfẹ́. \v 3 Se aápọn láti pa ìsọ̀kan ti Ẹ̀mí mọ́ níní ìdè ṣ`àláfìa. \ No newline at end of file diff --git a/04/04.txt b/04/04.txt new file mode 100644 index 0000000..f1bebc8 --- /dev/null +++ b/04/04.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 4 Ara kan ní ḿbẹ àti Ẹ̀mí kan, gẹ́gẹ́bí a se pè yín pẹ̀lú sínú ìrètí ìpè yín. \v 5 Bẹ́nì Olúwa kan ní ḿbẹ, ìgbàgbọ́ kan, ìtẹ̀bọmi kan, \v 6 Ọlọ́run kan àti Baba gbogbo gbò, tí ó ńse orí ohun gbogbo atì nípasẹ̀ ohun gbogbo nínú ohun gbogbo. \ No newline at end of file diff --git a/04/07.txt b/04/07.txt new file mode 100644 index 0000000..63aaf05 --- /dev/null +++ b/04/07.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 7 Fún ẹnìkọ̀kan wa ni a ti fún ní oore òfẹ́ gẹ́gẹ́bí ìwọ̀n ẹ̀bùn Krístì. \v 8 Gẹ́gẹ́bí ìwé mímọ́ se sọ: "Nígbàtí ó gòkè lọ sí àwọn ibi gíga, ó de ìgbèkùn ní ìgbèkùn, ó sì fi ẹ̀bùn fún ènìyàn." \ No newline at end of file diff --git a/04/09.txt b/04/09.txt new file mode 100644 index 0000000..cbcf54c --- /dev/null +++ b/04/09.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 9 Kí ni ìtumọ̀ wípé: "Ó gòkè," bíkòsepé ó sọ̀kalẹ̀ pẹ̀lú lọ sí ibi tí ó rẹlẹ̀ jùlọ nínú ayé? \v 10 Ẹnití ó sọ̀kalẹ̀, ohun kanna ni ẹnití ó gòkè rékọjá àwọn ọ̀run, kí ó baà le kún ohun gbogbo . \ No newline at end of file diff --git a/04/11.txt b/04/11.txt new file mode 100644 index 0000000..cfe96c9 --- /dev/null +++ b/04/11.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 11 Krístì fún àwọn ẹlòmíràn láti jẹ́ àpóstélì, àwọn miran wòólì, àwọn miran ajíhìnrere, àti àwọn miran olùsọ́àgùntàn àti olùkọ́ni. \v 12 Ó fi àwọn ẹ̀bùn isẹ́ wọ̀nyí fún ni láti dira isẹ́ fún àwọn ènìyàn mímọ́, àti fún ìmúdàgbà ara Krístì. \v 13 Ó tẹ̀síwájú láti mú ìdàgbàsókè bá ara rẹ̀ títí gbogbo wa yóò fi dé ìsọ̀kan ìgbàgbọ́ àti ìmọ̀ ọmọ Ọlọ́run, títí a ó fi dàgbà títí dé ìwọ̀n ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Krístì. \ No newline at end of file diff --git a/04/14.txt b/04/14.txt new file mode 100644 index 0000000..d50a809 --- /dev/null +++ b/04/14.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 14 Krístì mú wa dàgbà nítorí kí á má baà se mọ̀jèsín mọ́, tí a ń fi afẹ́fẹ́ tì síwá sẹ́yìn pẹ̀lú afẹ́fẹ́ ẹ̀kọ́ àti àrékérekè àwọn ènìyàn nínú ẹ̀tàn wọn. \v 15 Dípò èyí, kí á máa sọ òtítọ́ nínú ìfẹ́, a ní láti dàgbà ní gbogbo ọ̀nà nínú Rẹ̀, ẹnití íse orí, èyí ni Krístì. \v 16 Krístì ti kó gbogbo ara, ó sì ti soó pọ̀ nípa gbogbo ẹ̀yà ara, nígbàtí gbogbo wọn bá sisẹ́ papọ̀, èyí yóò mú kí ara dàgbà sókè nínú ìfẹ́. \ No newline at end of file diff --git a/04/17.txt b/04/17.txt new file mode 100644 index 0000000..6a0a5b8 --- /dev/null +++ b/04/17.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 17 Nítorínáà, mo wípé, mo sì tẹnumọ èyí nínú Olúwa pé: ẹ kò gbọdọ̀ gbé ìgbé ayé yín gẹ́gẹ́bí ti àwọn Kèfèrí nínú ìgbé ayé ọkàn wọn tí ó sófo \v 18 Òye won sókùnkùn, wọ́n se àjéjì sí ìgbé ayé tí ó wà nínú Ọlọ́run, nítorí òpè ni wọ́n nítorí ọkàn wọn sébọ́, ó sì le. \v 19 Wọn kò ní ìtìjú, wọ́n sì ti jọ̀wọ́ ara wọn fún ìsekúse, wọ́n sì tẹ̀síwájú láti máa se orísirísi àwọn n kan aláìmọ́. \ No newline at end of file diff --git a/04/20.txt b/04/20.txt new file mode 100644 index 0000000..5cda2bf --- /dev/null +++ b/04/20.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 20 Sùgbọ́n èyí kìí se ọ̀nà láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa Krístì. \v 21 Mo lérò wípé ẹ ti gbọ́ nípa Rẹ̀, àti wípé ati fi kọ yín gẹ́gẹ́bí òtítọ́ tí ó wà nínú Jésù. \v 22 Ati fi kọ́ yín láti bọ́ àwọn ìwà yín àtijọ́ sílẹ̀, láti bọ́ ògbólògbó ọkùnrin àtijọ́ náà sílẹ̀. Ọkùnrin ògbólògbó tí ó bàjẹ́ nítorí ẹ̀tàn ìfẹ́kùfẹ́ rẹ̀. \ No newline at end of file diff --git a/04/23.txt b/04/23.txt new file mode 100644 index 0000000..9da0f68 --- /dev/null +++ b/04/23.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 23 A ti kọ́ yín láti di titun nínú ẹ̀mí ọkàn yín, \v 24 Àti láti gbé ọkùnrin titun náà wọ̀ tí a ti dá ní àwòrán Ọlọ́run, ní òtítọ́, òdodo àti ìwà mímọ́. \ No newline at end of file diff --git a/04/25.txt b/04/25.txt new file mode 100644 index 0000000..1c8e3ba --- /dev/null +++ b/04/25.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 25 Nítorínáà, ẹ dágbére fún irọ́ gbogbo, kí ẹnì kọ̀ọ̀kan yín kí ó máa sọ òtítọ́ pẹ̀lú aládùúgbò, nítorí ẹ̀yà ara kannáà ni a jẹ́ fún ara wa. \v 26 Ẹ bínú, ẹ má sì se sẹ̀. Ẹ máse jẹ́ kí oòrùn wọ̀ bá ìbínú yín. \v 27 Ẹ máse fún èsù ní ààyè. \ No newline at end of file diff --git a/04/28.txt b/04/28.txt new file mode 100644 index 0000000..24ca2a2 --- /dev/null +++ b/04/28.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 28 Ẹnití ó n jalè, kò gbọdọ̀ jalè mọ́. Ó gbọ́dọ̀ sisẹ́, isẹ́ tí ó wúlò pẹ̀lú ọwọ́ ara rẹ̀, kí òun pẹ̀lú kí ó lè ní ohun tí ó lè pín pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn tí ó se aláìní. \v 29 Ẹ máse jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ìdíbàjẹ́ kan kí ó ti ẹnu yín jáde. Ẹ máa lo àwọn ọ̀rọ̀ tí ó lè gbé ni ró gẹ́gẹ́bí aìní olukúlùkù, kí ọ̀rọ̀ yín lè jẹ́ ìrànlọ́wọ́ fún àwọn tí ó bá ń gbọ́ yín \v 30 Ẹ má sì se mú Ẹ̀mímímọ́ Ọlọ́run bínú, nítorí nípasẹ̀ rẹ̀ ni a se èdìdí yín fún ọjọ́ ìràpadà. \ No newline at end of file diff --git a/04/31.txt b/04/31.txt new file mode 100644 index 0000000..d6639f4 --- /dev/null +++ b/04/31.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 31 Ẹ pa ìkorò, ìbínú, ìrúnú, ìjà, àti ìtẹ́mbẹ́lú ara ẹni sí apákan, pẹ̀lú ibi gbogbo. \v 32 Ẹ se inú rere fún ara yín, ẹ ní ìyọ́nú, ẹ dáríjìn ará yin gẹ́gẹ́bí Ọlọ́run nínú Krístì se dáríjìn yin. \ No newline at end of file diff --git a/04/title.txt b/04/title.txt new file mode 100644 index 0000000..dcff293 --- /dev/null +++ b/04/title.txt @@ -0,0 +1 @@ +Orí Ìkẹ́rin \ No newline at end of file diff --git a/05/01.txt b/05/01.txt new file mode 100644 index 0000000..f4dd9ac --- /dev/null +++ b/05/01.txt @@ -0,0 +1 @@ +\c 5 \v 1 Nítorínáà, ẹ se àfarawé Ọlọ́run, gẹ́gẹ́bí ọmọ ọ̀wọ́n. \v 2 Kí ẹ sì rìn nínú ìfẹ́, gẹ́gẹ́bí Krístì se fẹ́ wa tí ó sì jọ̀wọ́ ara rẹ̀ fún wa, crẹ òórùn dídùn àti ẹbọ fún Ọlọ́run. \ No newline at end of file diff --git a/05/03.txt b/05/03.txt new file mode 100644 index 0000000..d3132b5 --- /dev/null +++ b/05/03.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 3 Sùgbọ́n, kò gbọdọ̀ sí àmọ̀ràn kan nípa ìwà ìbàjẹ́ tí ìbánilòpọ̀, tàbí irúfẹ́ ìwà ìdọ̀tí tàbí ìjẹkújẹ, nítorí èyí kò tọ́ fún àwọn ènìyàn, Ọlọ́run mímọ́. \v 4 Kó má se sí èérí, kó má se sí ọ̀rọ̀ àlùfànsá tàbí àwọn àwàdà tí ó le - gbogbo àwọn tí kò tọ́, bíbẹ̀kọ́ ó yẹ kí á máa dúpẹ́. \ No newline at end of file diff --git a/05/05.txt b/05/05.txt new file mode 100644 index 0000000..792ae5c --- /dev/null +++ b/05/05.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 5 Kí èyí kí ó dá yín lójú, kò sí alágbèrè, aláìmọ́, tàbí oníjẹkújẹ kan - tí í se abọ̀rìsà - tí yóò ní ìpín kan ní ìjọba Krístì àti ti Ọlọ́run. \v 6 Kí ẹnikẹ́ni máse tàn yín jẹ pẹ̀lú ọọ̀rọ̀ kòròfo nítorí nkan wọ̀nyí ni ìbínú Ọlọ́run se ḿbọ̀ wá sórí àwọn ọmọ aláìgbọràn. \v 7 Nítorínáà ẹ mase darapọ̀ mọ́ wọn. \ No newline at end of file diff --git a/05/08.txt b/05/08.txt new file mode 100644 index 0000000..1a693d8 --- /dev/null +++ b/05/08.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 8 Nítorí ní ìgbàkan rí òkùnkùn ni yín, sùgbọ́n nísinsìnyí, ìmọ́lẹ̀ ni yín nínú Olúwa. Ẹ rìn gẹ́gẹ́bí ọmọ ìmọ́lẹ̀. ní yín, sùgbọ́n nísinsìnyí \v 9 (Nítorí èso ìmọ́lẹ̀ kún fún ìserere, òdodo, àti òtítọ́). \v 10 Kí ẹ sì máa wádì ohun tí ó wu Olúwa. \v 11 Ẹ máse darapọ̀ mọ́ àíleso isẹ́ òkùnkùn, sùgbọ́n ẹ kúkú máa se àfihàn wọn. \v 12 Nítorí ohun itìjú ni láti máa dárúkọ ohun tí wọ́n ńse ní ìkọ̀kọ̀. \ No newline at end of file diff --git a/05/13.txt b/05/13.txt new file mode 100644 index 0000000..581fe4f --- /dev/null +++ b/05/13.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 13 Sùgbọ́n nígbàtí ìmọ́lẹ̀ bá tàn, á fi ìríran hàn. \v 14 Nítorí´ ohun tí ó bá hàn ni ìmọ́lẹ̀. Nítorínáà ó wípé: "Jí ìwọ Olóorun, kí o sì dìde láàrin àwọn òkú, Krístì yóò tàn sí ọ. \ No newline at end of file diff --git a/05/15.txt b/05/15.txt new file mode 100644 index 0000000..b1ceadd --- /dev/null +++ b/05/15.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 15 Ẹ se àkíyèsí bí ẹ se ń gbé igbé ayé yín - kìí se gẹ́gẹ́bí àwọn aláìgbọ́n sùgbọ́n bí ọlọgbọ́n, \v 16 Ẹ ra ìgbà padà nítorí búburú ni àwọn ọjọ́. \v 17 Nítorínáà, ẹ máse se òmùgọ̀, sùgbọ́n ẹ ní òye ohun tí ìfẹ́ Ọlọ́run jẹ́. \ No newline at end of file diff --git a/05/18.txt b/05/18.txt new file mode 100644 index 0000000..9939ac4 --- /dev/null +++ b/05/18.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 18 Ẹ má sì se fi ara yín fún ọtí mímu, nítorí èyí á mú kí ènìyàn si ìwà hù, sùgbọ́n ẹ kúkú máa kún fún Ẹ̀mímímọ́. \v 19 Kí ẹ má bá ara yín sọ̀rọ̀ pẹ̀lú orin Psáàlmù àti àwọn orin, àti orin ẹ̀mi, kí ẹ máa kọ́ orin nínú ẹ̀mí sí Olúwa láti inú ọkàn yín wá. \v 20 Ẹ máa dúpẹ́ fún ohun gbogbo ní orúkọ Olúwa wa Jésù Krístì sí Ọlọ́run Baba náà. \v 21 Ẹ máa tẹríba fún ara yín pẹ̀lu ọ̀wọ̀ fún Krístì. \ No newline at end of file diff --git a/05/22.txt b/05/22.txt new file mode 100644 index 0000000..9622549 --- /dev/null +++ b/05/22.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 22 Ẹ̀yin aya ẹ jọ̀wọ́ ara yín fún àwọn ọkọ yín, gẹ́gẹ́bí fún Olúwa. \v 23 Nítorí ọkọ ní íse orí aya gẹ́gẹ́bí Krístì pẹ̀lú se jẹ́ orí fún ìjọ àti Krístì fúnrarẹ̀ ni Olùgbàlà ìjọ. \v 24 Gẹ́gẹ́bí ìjọ se jọ̀wọ́ ara rẹ̀ fún Krístì bẹ́ẹ̀ pẹ̀lu àwọn aya gbọ́dọ̀ jọ̀wọ́ ara wọn fún àwọn ọkọ wọn nínú ohun gbogbo. \ No newline at end of file diff --git a/05/25.txt b/05/25.txt new file mode 100644 index 0000000..40ead6f --- /dev/null +++ b/05/25.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 25 Ẹ̀yin ọkọ, ẹ fẹ́ran àwọn aya yín, gẹ́gẹ́bí Krístì ti se fẹ́ràn ìjọ tí ó sì jọ̀wọ́ ara rẹ̀ fún un. \v 26 Krístì jọ̀wọ́ ara Rẹ̀ fún ìjọ, kí ó ba lee sọọ́ dí mímọ́ lẹ́yìn tí ó ti sọọ́ di mímọ́ nípa íifi omi wẹ̀ẹ́ pẹ̀lú ọ̀rọ̀, \v 27 Kí ó baà le fii fún ara Rẹ̀ gẹ́gẹ́bí ìjọ tí´ ó lógo láìní àbàwọ́n tàbí ìdọ̀tí tàbí irú nkan báwonnì, sùgbọ́n mímọ́ láìní àbùkù. \ No newline at end of file diff --git a/05/28.txt b/05/28.txt new file mode 100644 index 0000000..9549273 --- /dev/null +++ b/05/28.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 28 Bákannáà àwọn ọkọ yẹ kí wọ́n fẹ́ràn àwọn aya wọn gẹ́gẹ́bí ara àwọn tìkárawọn. \v 29 Nítorí kò sí ẹnití ó jẹ́ kórira ara òun tìkárarẹ̀, bíkòse kí ó máa kẹ́ẹ, àti se ìtọ́jú rẹ̀, gẹ́gẹ́bí Krístì se ń kẹ́ ìjọ tí ó sì n tọ́jú rẹ̀. \v 30 Nítorí ẹ̀yà ara Rẹ̀ ni àwa. \ No newline at end of file diff --git a/05/31.txt b/05/31.txt new file mode 100644 index 0000000..d34fb58 --- /dev/null +++ b/05/31.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 31 "Nítorí ìdí èyí ọkùnrin yóò fi Baba àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, yóò sì darapọ̀ mọ́ ìyàwó rẹ̀, àwọn méjèjì yóò sì di ara kan." \v 32 Òtítọ́ tí ó pamọ́ yìí (jẹ́ èyí tí ó) ga - sùgbọ́n èmi ń sọ nípa Krístì àti ìjọ. \v 33 Síbẹ̀síbẹ̀, ẹnìkọ̀ọ̀kan yín pẹ̀lú gbọ́dọ̀ fẹ́ràn ìyàwó rẹ̀, gẹ́gẹ́bí ara òun tìkárarẹ̀, àti wípé ìyàwó náà gbọ́dọ̀ bọ̀wọ̀ fún ọkọ rẹ̀. \ No newline at end of file diff --git a/05/title.txt b/05/title.txt new file mode 100644 index 0000000..28131ab --- /dev/null +++ b/05/title.txt @@ -0,0 +1 @@ +Orí Karǔn \ No newline at end of file diff --git a/06/01.txt b/06/01.txt new file mode 100644 index 0000000..1462757 --- /dev/null +++ b/06/01.txt @@ -0,0 +1 @@ +\c 6 \v 1 Ẹ̀yin ọmọ, ẹ gbọ́ràn sí àwọn òbí yín nínú Olúwa, nítorí èyí yẹ. \v 2 "Bọ̀wọ̀ fún Bàbá àtí ìyá rẹ" (èyí ni òfin kinní pẹ̀lú ìlérí). \v 3 "Kí ó lè dára fún yín, kí ẹ sì leè ní ẹ̀mí gígùn nínú ayé." \ No newline at end of file diff --git a/06/04.txt b/06/04.txt new file mode 100644 index 0000000..603a28c --- /dev/null +++ b/06/04.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 4 Ẹ̀yin Baba, ẹ máse mú àwọn ọmọ yín bínú, sùgbọ́n, ẹ tọ́ wọn nínú àsẹ Olúwa. \ No newline at end of file diff --git a/06/05.txt b/06/05.txt new file mode 100644 index 0000000..e25ce22 --- /dev/null +++ b/06/05.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 5 Ẹ̀yin ọmọ ọ̀dọ̀, ẹ gbọ́ràn sí àwọn ọ̀gá yín nínú ayé pẹ̀lú ọ̀wọ̀ tí jinlẹ̀ àti ìwárìrì, nínú òtítọ́ ọkàn yín, Ẹ gbọ́ràn sí won bí ẹ ó se gbọ́ràn sí Krístì. \v 6 .Ẹ gbọ́ràn, kìí se nígbàtí ọ̀gá ń wò yín, kí ẹ ba leè mú inú wọn dùn, bíkòse pé kí ẹ gbọ́ràn bí ọmọ ọ̀dọ̀ Krístì, tí ó ń se ìfẹ́ Ọlọ́run láti inú ọkàn rẹ̀. \v 7 Ẹ se isẹ́ yín pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín, gẹ́gẹ́bí ẹnití ń sisẹ́ fún Olúwa tí kìí sì se ènìyàn. \v 8 Nítorí àwa mọ̀ pé ohun rere kóhun rere tí ẹnìkọ̀ọ̀kan bá se, yóò gbà èrè lọ́wọ́ Olúwa, ìbá se ẹrú tàbí òmìnira. \ No newline at end of file diff --git a/06/09.txt b/06/09.txt new file mode 100644 index 0000000..1a30ff4 --- /dev/null +++ b/06/09.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 9 Ẹ̀yin ọ̀gá, ẹ tọ́jú àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ bákannáà. Ẹ máse halẹ̀ mọ́ won. Ẹ kúkú mọ̀ wípé ọ̀gá ẹ̀yin méjèjì wà ní ọ̀run, kò sì sí ojúsàájú pẹ̀lú Rẹ̀ \ No newline at end of file diff --git a/06/10.txt b/06/10.txt new file mode 100644 index 0000000..cf95d8e --- /dev/null +++ b/06/10.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 10 Ní àkótán ẹ jẹ́ alágbára nínú Olúwa àti nínú agbára ipá Rẹ̀. \v 11 Ẹ gbé gbogbo ìhàmọ́ra Ọlọ́run wọ̀, kí ẹ̀yin kí ó leè dúró láti dojúkọ àrèkérekè èètò ti èsù. \ No newline at end of file diff --git a/06/12.txt b/06/12.txt new file mode 100644 index 0000000..785f6e0 --- /dev/null +++ b/06/12.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 12 Nítorí kìí se ẹran ara àti ẹ̀jẹ̀ ni àwa ḿbá jìjàdadì, bíkòse àwọn ìjọba, àwọn alásẹ, àti àwọn alákòso ẹ̀mí nínú òkùnkùn, àti àwọn ẹ̀mí búburú nínú àwọn ọ̀run. \v 13 Nítorínáà, ẹ gbé gbogbo ìhàmọ́ra Ọlọ́run wọ̀, kí ẹ̀yin kí ó leè dúró nínú àkókò ibi yìí, àti lẹ́yìn tí ẹ bá ti se ohun gbogbo tán, láti dúró gírí. \ No newline at end of file diff --git a/06/14.txt b/06/14.txt new file mode 100644 index 0000000..a9e96f5 --- /dev/null +++ b/06/14.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 14 Ẹ dúró, nítorínáà, lẹ́yìn ìgbà tí ẹ bá ti fi ọ̀já ìgbànú ti òtítọ́ àti ìgbayà tí òdodo nì mọ́ ara. \v 15 Bẹ́ẹ̀ni bàtà fún ẹsẹ̀ yín, ẹ gbé ìmúra tó setán láti polungo ìyìnrere ti àláìia wọ̀. \v 16 Ní gbogbo ohunkóhun ẹ mú apata ìgbàgbọ́, nípa èyí tí ẹ̀yin yóò fi leè pa iná àwọn ọfà ẹni ibi nì. \ No newline at end of file diff --git a/06/17.txt b/06/17.txt new file mode 100644 index 0000000..64f7878 --- /dev/null +++ b/06/17.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 17 Ẹ sì mú akoto ìgbàlà àti idà ẹ̀mí, tíí se ọ̀rọ̀ Ọlọ́run. \v 18 Pẹ̀lú gbogbo àdúrà àti ìsìpẹ̀, ẹ gbadúrà ní ìgbà gbogbo nínú Ẹ̀mí. Pẹ̀lú ọkàn yìí, ẹ má sọ́nà ní ìgbà gbogbo pẹ̀lú ìpamọ́ra gbogbo, gẹ́gẹ́bí ẹ se ń gbàdúrà fún gbogbo àwọn ènìyàn, Ọlọ́run, mímọ́ \ No newline at end of file diff --git a/06/19.txt b/06/19.txt new file mode 100644 index 0000000..8511e2c --- /dev/null +++ b/06/19.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 19 Kí ẹ sì gbàdúrà fún mi, pé kí á leè fún mi ní isẹ́ ìránsẹ́ kan nígbàtí mo bá ya ẹnu mi. Ẹ gbàdúrà pé kí n leè ma sọọ́ di mímọ̀ pẹ̀lú ìgboyà àwọn òtítọ́ náà tí ó pamọ́ nípa ìyìnrere. \v 20 Nítorí ìyìnrere ni mo se di ikọ̀ tí a pamọ́ nínú ìdè, kí n leè máa sọọ́ pẹ̀lú ìgboyà, gẹ́gẹ́bí ó se yẹ kí n sọ̀rọ̀. \ No newline at end of file diff --git a/06/21.txt b/06/21.txt new file mode 100644 index 0000000..1195b68 --- /dev/null +++ b/06/21.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 21 Tíkíkù, arákùnrin olùfẹ́, àti ìránsẹ́ olòótọ́ nínú Olúwa, yóò sọ ohun gbogbo fún yín, kí ẹ̀yin kí ó leè mọ̀ bí mo se ń se. \v 22 Mo ti rán an sí yín nítorí ìdí èyí, kí ẹ leè mọ̀ bí a se wà, kí òun kí ó leè mú yín lọ́kàn le. \ No newline at end of file diff --git a/06/23.txt b/06/23.txt new file mode 100644 index 0000000..93b878e --- /dev/null +++ b/06/23.txt @@ -0,0 +1 @@ +\v 23 Àláìia fún gbogbo àwon arákùnrin, àti ìfẹ́ pẹ̀lú ìgbàgbọ́ láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba àti Olúwa Jésù Krístì. \v 24 Ki ore ọ̀fẹ́ kí ó wà pẹ̀lú gbogbo àwọn tí ó fẹ́ Olúwa Jésù Krístì pẹ̀lú ìfẹ́ tí kìí kú. \ No newline at end of file diff --git a/06/title.txt b/06/title.txt new file mode 100644 index 0000000..ef6d347 --- /dev/null +++ b/06/title.txt @@ -0,0 +1 @@ +Orí Kẹfà \ No newline at end of file diff --git a/LICENSE.md b/LICENSE.md new file mode 100644 index 0000000..98f733d --- /dev/null +++ b/LICENSE.md @@ -0,0 +1,29 @@ + +# License +## Creative Commons Attribution-ShareAlike 4.0 International (CC BY-SA 4.0) + +This is a human-readable summary of (and not a substitute for) the full license found at http://creativecommons.org/licenses/by-sa/4.0/. + +### You are free to: + + * **Share** — copy and redistribute the material in any medium or format + * **Adapt** — remix, transform, and build upon the material + +for any purpose, even commercially. + +The licensor cannot revoke these freedoms as long as you follow the license terms. + +### Under the following conditions: + + * **Attribution** — You must attribute the work as follows: "Original work available at https://door43.org/." Attribution statements in derivative works should not in any way suggest that we endorse you or your use of this work. + * **ShareAlike** — If you remix, transform, or build upon the material, you must distribute your contributions under the same license as the original. + +**No additional restrictions** — You may not apply legal terms or technological measures that legally restrict others from doing anything the license permits. + +### Notices: + +You do not have to comply with the license for elements of the material in the public domain or where your use is permitted by an applicable exception or limitation. + +No warranties are given. The license may not give you all of the permissions necessary for your intended use. For example, other rights such as publicity, privacy, or moral rights may limit how you use the material. + +This PDF was generated using Prince (https://www.princexml.com/). diff --git a/front/title.txt b/front/title.txt new file mode 100644 index 0000000..52cb764 --- /dev/null +++ b/front/title.txt @@ -0,0 +1 @@ +Éfésù \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json new file mode 100644 index 0000000..7ac3b2d --- /dev/null +++ b/manifest.json @@ -0,0 +1,108 @@ +{ + "package_version": 6, + "format": "usfm", + "generator": { + "name": "ts-desktop", + "build": "5" + }, + "target_language": { + "id": "yo", + "name": "Yorùbá", + "direction": "ltr" + }, + "project": { + "id": "eph", + "name": "Ephesians" + }, + "type": { + "id": "text", + "name": "Text" + }, + "resource": { + "id": "reg", + "name": "Regular" + }, + "source_translations": [ + { + "language_id": "en", + "resource_id": "ulb", + "checking_level": "3", + "date_modified": "2017-11-29T00:00:00+00:00", + "version": "12" + } + ], + "parent_draft": {}, + "translators": [ + "emmanuel oyemomi" + ], + "finished_chunks": [ + "front-title", + "01-title", + "01-01", + "01-03", + "01-05", + "01-07", + "01-09", + "01-11", + "01-13", + "01-15", + "01-17", + "01-19", + "01-22", + "02-title", + "02-01", + "02-04", + "02-08", + "02-11", + "02-13", + "02-17", + "02-19", + "03-title", + "03-01", + "03-03", + "03-06", + "03-08", + "03-10", + "03-12", + "03-14", + "03-17", + "03-20", + "04-title", + "04-01", + "04-04", + "04-07", + "04-09", + "04-11", + "04-14", + "04-17", + "04-20", + "04-23", + "04-25", + "04-28", + "04-31", + "05-title", + "05-01", + "05-03", + "05-05", + "05-08", + "05-13", + "05-15", + "05-18", + "05-22", + "05-25", + "05-28", + "05-31", + "06-title", + "06-01", + "06-04", + "06-05", + "06-09", + "06-10", + "06-12", + "06-14", + "06-17", + "06-19", + "06-21", + "06-23" + ] +} \ No newline at end of file