yo_php_text_ulb/02/19.txt

1 line
455 B
Plaintext

\v 19 Ṣùgbọ́n èmi ní ìrètí nínú Jésù Olúwa láti rán Tìmótíù sí yín láìpẹ̀ yìí, kí èmi kí ó le ní ìmúlọ́kànle nígbàtí mo bá mọ bí ǹkan ṣe ń lọ pẹ̀lú yín. \v 20 Nítorí èmi kò ní ẹlòmíràn tí ó dàbí rẹ̀, tí ọ̀rọ̀ yín ká lára nítòótọ́. \v 21 Nítorí gbogbo wọn ń lépa àwọn ìfẹ́ ọkàn tara wọn, wọn kò sì lépa àwọn ǹkan ti Jésù Krístì.