yo_php_text_ulb/02/01.txt

1 line
368 B
Plaintext

\c 2 \v 1 Bí ìgbaniníyànjú kan bá wà nínú Krístì, bí ìtùnú kan bá wà nínu ìfẹ́ Rẹ̀, bí ìfarakínra kankan bá wà pẹ̀lú Ẹ̀mí, bí àánú àti ìkáàánu kan bá sì wà, \v 2 ǹjẹ́ ẹ mú ayọ̀ mi kún nípa ríronú bákan naa, níní ìfẹ́ kan naa, níní ìrẹ́pọ̀ ti ẹ̀mí, àti níní àfojúsùn kan náà.