yo_php_text_ulb/04/21.txt

1 line
322 B
Plaintext

\v 21 Ẹ kí olúkúlúkù onígbàgbọ́ nínú Krístì Jésù. Àwọn arákùnrin tí wọ́n wà pẹ̀lú mi ń kí yín. \v 22 Gbogbo àwọn onígbàgbọ́ níbí ń kí yín, pàápàá jùlọ àwọn ará ilé Késárì. \v 23 Kí oore-ọ̀fẹ́ Olúwa Jésu Krístì wà pẹ̀lú ẹ̀mí yín. Àmin.