Tue Oct 08 2019 07:01:39 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
d4d64ddf45
commit
93b1bb163c
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\c 3 \v 1 Níparí, ẹ̀yin ará mi, ẹ yọ̀ nínú Olúwa. Kò ni mí lára láti kọ̀wé àwọn nǹkan woǹyí kan nán aǹ sí yín lẹ́kàn náà si. Àwọn nǹkan wọ̀nyí yíò pa yín mọ́. \v 2 Ẹ ṣọ́ra fún àwọn ajá. Ẹ ṣọ́ra fún àwọn oníṣẹ́ ibi. Ẹ ṣọ́ra fún àwọn tí wọ́n ń panilára. \v 3 Nítorí àwa ni olùkọlà. Àwa ni à ń sìn nípa Ẹ̀mí Ọlọ́run. Àwa ni à ń ṣògo nínú Krístì Jésù, tí
|
||||
\c 3 \v 1 Níparí, ẹ̀yin ará mi, ẹ yọ̀ nínú Olúwa. Kò ni mí lára láti kọ̀wé àwọn nǹkan woǹyí kan nán aǹ sí yín lẹ́kàn náà si. Àwọn nǹkan wọ̀nyí yíò pa yín mọ́. \v 2 Ẹ ṣọ́ra fún àwọn ajá. Ẹ ṣọ́ra fún àwọn oníṣẹ́ ibi. Ẹ ṣọ́ra fún àwọn tí wọ́n ń panilára. \v 3 Nítorí àwa ni olùkọlà. Àwa ni à ń sìn nípa Ẹ̀mí Ọlọ́run. Àwa ni à ń ṣògo nínú Krístì Jésù, tí a kò sì gbékẹ̀lé ẹran ara.
|
Loading…
Reference in New Issue