yo_eph_text_ulb/01/17.txt

1 line
262 B
Plaintext

\v 17 Mo ngbadura wipe ki Olorun Oluwa wa Jesu Kristi, Baba Ogo, ki o fun yin ni emi ogbon ati ifihan ninu imo re. \v 18 Mo ngbadura wipe ki oju inu okan yin ki ole riran, ki eyin ki oni imo ireti eyi ti o fi pe yin ati opolopo ogun ti awon eniyan mimo Olorun ni